Kayamata: Ṣé lóòótọ́ ni Kayamayo wà táwọn ọkùnrin ń lò láti wọ́nà àbáyọ sí Kayamata?
Ni bii ọdun melo kan ni ariwo sọ lori ayelujara nipa amulo Kayamata eyi to ni ọpọ itumọ si awọn eeyan.
Se ẹyin ti gbọ nipa Kayamata ri, ki ni itumọ rẹ si yin, ero wo si lo maa n wa sọkan yin, tẹ ba ti gbọ orukọ yii?
Ọna lati wa idahun sawọn ibeere yii lo mu ki BBC Yoruba bọ sigboro lati se ẹkunrẹrẹ iwadii nipa eroja Kayamata yii ati isẹ to n se.
- Iná ń yọ látara òkúta, ṣé iná yìí lè pèsè iná ọba bí-
- Ìjà dópin, wo ọ̀nà tí òṣèré-bìnrin Yewande Adekoya àti ọkọ rẹ̀ gbà parí ìjà tó tú wọn ká
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- -Ìjọba Benue ló ní ká kuró, tí àdó olóró fi pa Fulani 27, tí ọ̀pọ̀ sì farapa-
- Òkò ba òǹlàjà lórí lásìkò tò ń la ìja, ikú dé
- Ààyè ní mó gbé ìyàwó mi délé ìwòsàn àmọ́ wọ́n kọ̀ láti tọ́jú rẹ̀ tó fi kú - Ọkọ Bolanle Raheem
Bakan naa la tun wadi pe se lootọ ni Kayamata jẹ oogun abẹnu gọngọ to wa lati fa ọkunrin mọra, ti ko fi ni bọ kuro lọwọ obinrin to ba lo eroja naa fun.
Ninu iwadii wa, se la tun gbọ pe eroja miran tun wa ti wọn n pe ni Kayamayo eyi ti wọn ni awọn ọkunrin n lo bii adodun, gẹgẹ bii ọna abayọ si Kayamata .
Sugbọn ọna lati fi idi ododo mulẹ nipa Kayamata lo gbe wa de ọdọ obinrin Hausa kan to n ta eroja naa, Hajiya Muhammed, ẹni to fidi rẹ mulẹ pe ede Hausa ni Kayamata, to si sọ itumọ rẹ.
Bakan naa lo sọ bi wọn se n lo eroja naa ati pataki rẹ fun lọkọlaya.
- Dibu Ojerinde lò mí láti kó N5.2bn owó ìjọba ṣàpó ara rẹ̀ - Ẹlẹ́rìí sọ fún iléẹjọ́
- Ọ̀pọ̀ òṣèré tíátà ń bá Tinubu polongo ìbò, akẹẹgbẹ́ wọn sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí wọn
- Ọwọ́ agbófinró tẹ bàbá tó fipá bá ọmọ rẹ, ọmọ ọdún mọ́kànlá lòpọ̀ nílùú Ibadan
- Ìyá-ìyàwó kọ ọkọ sílẹ̀ láti fẹ́ ọkọ-ọmọ rẹ̀ ni ariwo bá ta
- Ọmoͅ osͅù méͅfà kú lórí èͅsùn pè ìyá rèͅ fun ní òògùn olóró ‘Tramadol’
Awọn ọkunrin ati obinrin naa tun ba BBC Yoruba sọrọ lori ero wọn nipa Kayamata, oju ti wọn fi lo amulo rẹ laarin takọ-tabo.
Ko tan sibẹ, a tun ba dokita onisegun oyinbo sọrọ, ẹni to salaye ohun ti Kayamata jẹ lede oyinbo, iwulo rẹ ati iwadii nipa rẹ.
Fidi yii, ọpọ ọgbọn ati iroyin awogbadun lo wa nibẹ, ẹ wo o.