Abdul Hakeem Oladimeji Lawal: Kò sí ǹkan tí kò mẹ́hẹ ní Kwara lásìkò yìí
Ṣe toripé baba mi ṣe gomina ri ko sọ pe ki emi naa ma dije dupo to wu mi ti mo ba ni nkan lọkan lati ṣe fun awọn eniyan Kwara?- Hakeem Lawal
Oludije labẹ ẹgbẹ oṣelu Social Democratic Party ni ipinle Kwara to wa ni aarin gbungbun Naijiria, Abdulhakeem Oladimeji Mohammed gbalejo BBC Yoruba.
O ṣalaye ohun to ni lọkan lati ṣe fawọn oludibo ni Kwara ti oun ba wọle gẹgẹ bii gomina ipinlẹ naa ninu idibo to mbọ.
Hakeem ṣalaye pe nitootọ ni oun kere lọjọ ori ṣugbon oun mo nkan ti ohun fẹ ṣe yatọ pẹlu iriri oun ni Kwara.
Bakan naa lo mẹnuba gbogbo ipenija to n koju awọn eeyan Kwara lasiko yii ati ohun ti oun le ṣe ni ọna abayọ.
- Ǹjẹ́ ìjọba àpapọ̀ ti fowó kún owó epo bẹntírò-
- Ìjọba South Africa já iná mọ̀nàmọ́ná ‘embassy’ Naijiria lẹ́yìn to jẹ gbèsè $23,000 owó iná
- Mo máa dín owó orí àwọn olókowò kéékééké kù tí mo bá wọlé- Adelabu Accord Party
- Àwọn iléẹjọ́ Sharia rí ẹ̀wọ̀n he lórí ẹ̀sùn pé wọ́n gba rìbá N500m
- Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa ààrùn Diphtheria tó ti pa èèyàn 25 ní Kano
- Wo àkójọpọ̀ ìlérí táwọn olùdíje gómìnà l‘Oyo ṣe fáráàlú níbi ìpàdé ìta gbangba BBC Yorùbá
- Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọ́sìn, palẹ̀mọ́ olùjọ́sìn 25 ni Katsina
- APC Osun kéde aàwẹ̀ àti àdúrà ọjọ́ méje kí 'tribunal' lè gbé ipò gómínà padà fún Oyetola
- Ọwó agbófinró tẹ Ọba méjì lórí ìjínigbé tó wáyé ní ojú irin ní ìpínlẹ̀ Edo