Lukman Oyebisi Ilaka: Kò yẹ kó sí túlààsí, ìjà tàbí dídáná sunlé ara ẹni nítorí ibò

Àkọlé fídíò, Lukman Oyebisi Ilaka: Kò yẹ kó sí túlààsí, ìjà tàbí dídáná sunlé ara ẹni nítorí ibò

Emi àti Makinde jọ ròó, a dẹ jọ pinnu pe mo ṣetan lati jade dupo senatọ- Bisi Ilaka

Ogbeni Lukman Oyebisi Ilaka to n dije dupo sẹnẹtaọ Oyo ṣlaaye ohun to fẹ́ ṣe fun ara ilu fún BBC Yoruba.

O sọ nipa irinajo rẹ lati oke okun pada wa sile ati awọn iṣẹ to ti ṣe sẹyin laarin awọn eeyan Oyo to fẹ lọ ṣoju fun.

Ilaka menuba iwa aidara ti awọn mi to jẹ aṣoju n hu si ara ilu ti ko mu idagbasoke dani.

O ṣeleri lati soju awọn eeyan Oyo daadaa ki inu oludibo loe dun.

Agbẹjọrọ yii sọ iriri rẹ ati awọn ona idagbasoke to fẹ mu gun.