Àwọn eèyàn PDP àti APC ti ba ǹkan jẹ́ púpọ̀ ni mo ṣe kúrò níbẹ̀- Rabiu Kwankwaso
Kwankwaso ṣalaye idi to fi kuro ni PDP lọ si APC ko to tun lọ da ẹgbẹ oselu NNPP silẹ.
BBC gbalejo Rabiu Kwankwaso to jẹ oludije sipo aarẹ Naijiria labẹ ẹgbẹ oṣelu New Nigeria People's Party (NNPP).
O ni pe ọpọ lo maa n fi oju tẹmbẹlu oun sẹyin ṣugbon nkan ti yatọ bayii.
O salaye idi to fi kuro lẹgbẹ oselu PDP ati APC ko to di oludije ẹgbẹ NNPP bayii.
- Wo bi o ṣe lè wo orúkọ rẹ nínú àkọsílẹ̀ olùdìbò tí I-NEC gbé jáde
- 'Nítorí owó kọ́ ni mo ṣe n fi èdè Ikalẹ kọ́ àgbàlagbà ní àṣà Yorùbá láì wo ìwé'
- Ohun tó fa rògbòdìyàn lẹ́yìn tí wọ́n yan Ọba tuntun ní Ikirun rèé
- 'À-wọn obìnrin tó n fi ọṣẹ tó ní kẹ́míkà sí irun wà nínú ewu jẹjẹrẹ ilé ọmọ'
- Ẹ̀yin gómìnà, ẹ fún wa láàyè láti kojú àwọn agbébọn lòpópónà Èkó sí Ìbàdàn
- Kò dín ní ogún èèyàn àti oͅkòͅ 30 tó jóná nínú ìbúgbàmù ní Kogi
Kwankwaso ni pe inu oun dun pe oun si ni iwa ọmọluwabi titi di asiko lainaani iwa buruku awọn oloṣelu mii.
O ni pe igbagbo oun ni pe nakn maa yipada ninu idibo 2023 nitori pe awọn ara ilu lo maa dibo yan awọn ti wọn n fẹ kii se ọlọjẹlu mọ.
Kwankwaso sọ idi to fi da ẹgbẹ NNPP sile ati ibi ti ọrọ iṣelu Naijiria de duro bayii.