BBC Africa Eye ṣe ìwádìí ohun tí ojú ọmọ ọ̀dọ́ ń rí ní Kenya
Opọ lo maa n san iye owo tó kere pupọ fun awọn ọmọ ọdọ wọn
Ikọ iwaddi ijinlẹ BBC Africa Eye ṣe iwadii ohun ti oju awọn ọmọdọ kan n ri ni Kenya.
Mercy Nwaku to jẹ ọkan lara wọn lo pada gbe ọga rẹ lọ sile ẹjọ fun ẹsun ifiyajẹni.
Lẹyin ọdun merin ni ile ẹjọ da ẹjọ pe oga Mercy maa lọ ni alaafia.
- Kanu kọ̀ láti farahàn ní ilé ẹjọ́, Adájọ́ sún ìgbẹ́jọ́ sí ọjọ́ míràn ọjọ́ ire
- Iléeṣẹ́ ọmọ ogun kéde orúkọ agbésùnmọ̀mí 19, àti ẹ̀bùn owó ₦-5m fún ẹni tó bá lè ṣamọ̀nà bí ọwọ́ yóò ṣe tẹ̀ wọ́n
- Àwọn Olóṣèlú ti ba ǹkan jẹ́ jú ní Nàìjíríà, Yorùbá ló kàn ṣùgbọ́n....- Adewole Adebayo
- Ninalowo ra ilé ńlá fún aya rẹ̀ láti sàmì ọdún 18 lẹ́yìn ìgbéyàwó
- Ìmọ̀ àìsàn ìtọ̀ ṣúgà tí kò kún tó ló ń fa ikú àìtọ́jọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀-Obasanjo
- Ọ̀lẹ ní àwọn DSS ní Naijiria, TV ni wọ́n máa ń wò nígbà tí mo wà ní páńpẹ́ wọn- Ṣowore
Nibayii, Mercy ti kawe tan, o si ti di ọga iṣe ara rẹ ti o ti n se ounjẹ lorisiirisii bo ti wuu.
Edith Muogo to jẹ alabojuto ile ti won ti n daabo bo awọn ọmọ ọdọ ti ọga wọn n fiya jẹ naa salaye awon igbese ti won n gbe fun BBC.
Eyi jẹ iwuri lori irinajo Mercy lati ọmọ ọdọ di oga iṣẹ ara rẹ
Iwọ tto ba jẹ ọmọ ọdo lasiko yii, mase ro ara rẹ pin.
Bawo ni iwọ naa ṣe n toju ọmọ ọdọ re?