Funke Felix Adejumo: Èmí kìí gba owó oṣù lọ́wọ́ ìjọ kankan, oníṣòwò gidi ni mi
Ti ìmúra rẹ̀ bá ti tẹ́ Olorun, ọkọ rẹ ati iwọ funra rẹ lọrun, ariwo lasan ni eyi to ku- Funke Felix Adejumo
Oniwaasu Funke Felix Adejumo salaye pe ọtọ ni aaye obinrin gẹgẹ bi iya, iyawo, iya iya ọmọde, oniwaasu ati oniṣowo.
Bakan naa ni ogbontarigi oniwaasu lori ọrọ idile ati ibaṣepọ laarin lọkọlaya yii tun yanana mimọ iyatọ ipo ti eeyan ba n ṣoju fun.
O fi ara rẹ ati ọkọ rẹ Bisọọbu Felix Adejumọ ṣe apẹẹrẹ pe ọtọọtọ ni ipo ati aaye kaluku ninu ijọ ati nibi gbogbo.
- Àwọn eèyàn máà ń sá fún mi, bẹ́ẹ̀ èmi ni mo sọ arà mi ní Agbákò- Charles Olumo
- Títí di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yìí, èmi gan an kò mọ irú ẹni tí Wole Soyinka jẹ́- Ojọ̀gbọ́n Wole Soyinka
- Owó ló ń jọba nínú ìṣèlú Nàìjíríà kìí ṣe ọpọlọ tàbí ìrírí mọ́- Anisulowo Iyabo
- Ṣé ìwọ mọ ìtàn Ọdẹ tó tẹ Ẹ̀pẹ́ dó láti ìgbà ìwásẹ̀?
- Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ẹ̀yà kan wà ní Africa, tó jẹ́ akọ́sẹ́mọsẹ́ nípa sí sọ nkan ọmọkùnrin di nla ní ìlànà ìbílẹ̀?
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Igbo Olodumare rèé, níbi tí Ìgbín ti tóbi ju Ìjàpá lọ
- Ìdí tí àwọn ìbejì mi, Twinz love ṣe ń rí mi mú fi ṣe “prank” wọn rèé – Ìyá Ìbejì
- Ọ̀dọ́mọdébìnrin tó fí gbọ̀ọ̀rọ́ jẹkà nidi iṣẹ́ mọ́káliíkì
- Wo bí Pásítọ̀ Adeboye, Wòlíì Iginla ṣe ń dárò ikú akẹgbẹ́ wọn David Yonggi Cho
- Kini Yoruba ‘International passport’?
- Wo ilé Adebisi Idikan n‘Ìbàdàn, àwòdamiẹnu ni
Ni afikun, Arabinrin Funke Felix Adejumo menuba awọn inawo to so mọ awọn oniwaasu nigba to n fi ara re se apẹẹrẹ.
O ni ko si bi eeyan ṣe le tẹ araye lọrun ṣugbọn onikaluku nilo ọgbọn Olorun lati dari aye rẹ ati awọn igbesẹ to yẹ ni gbigbe