Gomina Adegboyega Oyetola sọ ibi ti iṣẹ́ dé dúró nípinlẹ̀ Osun lórí ètò BBC Yoruba

Àkọlé fídíò, Gomina Adegboyega Oyetola sọ ibi ti iṣẹ́ dé dúró nípinlẹ̀ Osun lórí ètò BBC Yoruba

Emi kii parọ rara, ohun ti mo ba fẹ́ ṣe ni mo maa n sọ- Gomina Oyetola

BBC Yoruba seto ipade itagbangba nilu Osogbo ni ipinle Osun ki awon oludibo le raaye mọ sii nipa awọn oludije sipo gomina nibẹ.

Lara awọn to wa sibi eto naa ni Gomina Adegboyega Oyetola to n tuko ipinle Osun bayii.

Lati ọdun 2018 ni gominaa naa ti gori aleefa lẹyin ti Ogbeni Rauf Aregbesola fi ipo naa silẹ,.

Adegboyega Oyetola salaye nipa awon ileri rẹ to ti muṣẹ lati igba to ti gori aleefaGbọ́ ohun tí àwọn olùdíje sípò gómìnà ìpínlẹ̀ sọ níbi ìtàkurọ̀sọ BBC Yoruba.