Ara: Láti kékeré ni mo ti ń lu ìlú pẹ̀lú ayọ̀
Emi gangan ni Àrà -Aralola.
Àrà rèé, ogbontarigi ayanbinrin ti gbogbo eeyan mọ pẹlu ilu lilu kaakiri agbaye.
O ba BBC Yoruba sọrọ lori bi oun ṣe bẹrẹ lati kekere titi di ibi ti Ẹlẹda ran oun lọwọ de bayii.
- Ẹ̀kọ́ mẹ́jọ tó yẹ kí ilẹ̀ Afirika kọ́ lára àjàkálẹ̀ aàrùn coronavirus
- Ọlọ́run ló ní kí Abacha kú, àwọn àgbà Yorùbá púpò kò bá ṣòfò- Dele Momodu
- Mo kọ̀ láti ṣe àpèjẹ 'Reception' lẹ́yìn ìgbéyàwó mi nítorí...
- Àbòsí ló fa ìjà láàrin èmi àti Ajimobi kìí ṣe ọ̀rọ̀ NYSC -Shittu
- Owó bọ̀ọ̀lì ni mo fi rán ọmọ mi mẹ́rin jáde ilé ìwé gíga -Grace
- Ọmọ ọdún méjìlá ni mo ti ń ṣe bàálù, ọkọ̀, ilé àti ọkọ̀ ojú omi - Ọdọ́mọdé ‘Engineer’
- Omijé bọ lójú mí nígbà tí wọn n kọ orin ilẹ̀ wà
Bakan naa ni Àrà ti orukọ rẹ n jẹ Aralọla Olamuyiwa lapeja sọrọ lori ọmọbinrin mii to n lu ilu bii tirẹ.
O ni Àrá ni orukọ ọmọ Igbo naa n jẹ ati pe ọna ilu lilu awọn yatọ sira wọn.
Ara sọrọ lori bi aisan ṣe sọ oun di olominira lọwọ baba oun ti ko kọkọ fẹ faramọ orin kikọ ati ilu lilu fun oun.
O rọ awọn ololufẹ rẹ lati má ṣi oun mu mọ fun Àrá nitori ọtọ ni tọ́lú ọtọ dẹ ni tọ̀lù ni awọn mejeeji.