Tani otutu ma n mu ju laarin Ọkunrin ati Obinrin?

Àkọlé fídíò, Tani otutu ma n mu ju laarin Ọkunrin ati Obinrin?

Awọn iyatọ to wa ni ara Ọkunrin ati Obinrin ,paapa ọwọ ati ẹsẹ lo ma n sokunfa bii otutu se n mu Obinrin ju Ọkunrin lọ.

Amin iyasọtọ kan

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si:

Amin iyasọtọ kan