Inú APC ń dùn nígbà tí ayọ̀ PDP kò kún lórí ìdájọ́ náà
Ilé ẹjọ́ tó ń gbọ́ ìgbẹ́jọ́ ìdìbò aarẹ Naijiria ti dá ẹjọ ti oludije PDP, Abubakar Atiku pe lórí ìdìbò aarẹ 2019 nù ní Abuja.