You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Real Madrid vs Liverpool: Salah parí ìrìnàjò Champions league
Mohammed Salah ti jade kuro ninu papa iṣire ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba laarin Real madrid ati Liverpool.
Salah to jẹ ogunna gbongbo agbabọọlu Liverpool jade kuro lori papa lẹyin ti o ti fi apa rẹ ṣeṣe ninu ifẹsẹwọnsẹ naa.
Salah jẹ ọkan lara awọn irawọ agbabọọlu ti awọn eeyan n woye pe yoo tan bi oorun ninu ifẹsẹwọnsẹ naa.
Ọgbọn iṣẹju ni ifẹsẹwọnsẹ naa de nigba ti o jade.
Ẹkunrẹrẹ iroyin laipẹ