Joe Biden Innauguration, Jill Biden: Tani ìyàwó Joe Biden tí yóò jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ nílẹ̀ Amẹrika?

Àkọlé fídíò, Joe Biden Innauguration: Tani ìyàwó Joe Biden tí yóò jẹ obìnrin akọ̀kọ nílẹ̀ Amẹrika?

Jill Biden yoo di obinrin akọkọ lorilẹede Amẹrika lẹyin ti wọn ba bura fun Joe Biden gẹgẹ bi aarẹ aata ti yoo jẹ lorilẹede Amerika.

Jill Biden si ni iyawo aarẹ akọkọ lorilẹede Amerika ti yoo jẹ ọjọgbọn pẹlu Iwe eri mẹrin to fi mọ Phd.

Bakan naa si ni yoo jẹ ẹni akọkọ ti yoo ma a ṣiṣẹ oojọ rẹ yatọ si ti ileeṣẹ ijọba, White House.

Ẹ wo awọn ohun miran to yẹ ki ẹ mọ nipa Jill Biden...