Ǹjẹ́ àrùn Coronavirus leè wà lára èèyàn títí lái?
Lẹyin ti arun Coronavirus tan de Naijiria, oriṣiriṣi awọn ahesọ ọrọ lo ti n tan kalẹ lori itakun ayelujara.
Lara rẹ ni pe ti eeyan ba ti le lugbadi arun naa, irufẹ ẹni bẹ ko ni le bọ ninu rẹ titi lailai.
Ajọ eleto ilera agbaye, WHO ti sọ pe ko si otitọ ninu ahesọ bẹ.
- Omololu Olunloyo Kọmíṣọnnà lẹẹmẹfà tó gbé ọpá àṣẹ fún aláàfin Oyo àti Ṣọun Ogbomọṣọ
- N1000 tí Ọlọ́pàá ń gbà lẹ́nubodè wa làrùn Coronavirus fi ráyè wọlé-Ìjọba ìpínlẹ̀ Oǹdó
- Gómìnà Makinde, pe Sunday Igboho àti Auxilliary kóo parí ìjà wọn, àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ jáde
- Akojọpọ ǹkan amáyedẹrùn tí ijọba ti fun awọn ọmọ Naijiria nitori aarun coronavirus
Ṣugbọn ṣe o ṣeṣe ki arun naa wọle si eeyan lara lẹyin to ba ti bọ lọwọ rẹ tan?
Alaye ni kikun wa ninu fidio yii.