World Cup 2018: Wo Jẹẹsí to n pe Jẹẹsi ransẹ ní Russia

Gbogbo awọn orileede to n kopa ni idije ife agbaye Russia 2018, ti fi jẹẹsí wọn han saaju idije naa.

Wọnyi ni aworan gbogbo awọ́n jeesi ti iko kookan yoo wo to fi mo Jẹẹsí orileede Naijiria ti won ti ra millionu meta ninu re.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Isọri Kinni-in:

Orilẹede Russia

Orilẹede Saudi Arabia

Orilẹede Egypt

Orilẹede Uruguay

Isọri Keji:

Orilẹede Portugal

Orilẹede Spain

Orilẹede Morocco

Orilẹede Iran

Isọri Kẹta:

Orilẹede France

Orilẹede Australia

Orilẹede Peru

Orilẹede Denmark

Isọri Kẹrin:

Orilẹede Argentina

Orilẹede Iceland

Orilẹede Croatia

Orilẹede Nigeria

Isọri Karun-un:

Orilẹede Brazil

Orilẹede Switzerland

Orilẹede Costa Rica

Orilẹede Serbia

Isọri kẹfa:

Orilẹede Germany

Orilẹede Mexico

Orilẹede Sweden

Orilẹede South Korea

Isọri keje:

Orilẹede Belgium

Orilẹede Panama

Orilẹede Tunisia

Orilẹede England

Isọri Kẹjọ:

Orilẹede Poland

Orilẹede Senegal

Orilẹede Colombia

Orilẹede Japan

Gbogbo awọn aworan naa wa lati ọwọ Simon Hofmann fun ajoelere bọọlu lagbaye, Fifa.