10bn Loan: Mọ̀ ohun tí àwọn ará ìpínlẹ̀ Kano ń sọ nípa owó tuntun tí Ganduje fẹ́ yá

aworan gomina ipinlẹ kano

Oríṣun àwòrán, screenshot

Ni ipinlẹ Kano, opo ara ilu ti bu enuatelu bi ijọba ipinlẹ labe isakose Gomina Abdullahi Umar Ganduje se n gbero lati ya owo toto bIlonu mewaa naira lati se afikun irinsẹ igbalode lati fi koju dukiẹkudiẹ eto abo ni ipinlé naa

Ile gbimo aṣofin ipinlẹ Kano ti buwolu yiya owo toto bilonu mewaa lati ra awọn ohun iririru irinsẹ igbalode bi ẹro ‘’CCTV’ lati se afikun di didabo ni ipinlẹ naa’

Ookan lara awọn ọmọ ile gbinmo aṣofin, Abdu Madari ninu alaye rẹ fun BBC Hausa ni ipinlẹ Kano lilo awọn iransẹ igbalode lati gbogun ti ẹto abo ni agbegbe ipinlẹ naa.

“Lara nnkan ti a fẹ fi owo naa ra ni ẹro ‘CCTV’ ati ilegbe fun ibi ipamọ data fujn awọn ẹleso abo lati se ise wón dada “

Ọpọlọpọ ẹgbẹ aladani ni wọn ti pẹ akesi ijọba ipinlẹ Kano bi gbese se n gori gbese ni ipinlẹ naa.

Wọn ni ọpọlọpọ igba ni ijọba ipinlẹ naa ti ya iriru owo naa lati fi mu iyipada ba ẹto ẹko sugbọn ti so eso rere nigbeyin.

Asiwaju ẹgbẹ alatako ni ipinlẹ Kano, Barrister Maryam Abubakar, ni oun ko ri idi ti ijóba ipinlẹ naa fi ko si ninu gbese nitori pẹ nnkan miiran wa ti o yẹ ki ijọba dojuko ni ipinlẹ Kano.

aworan gomina kano ati olujide egbe aarẹ oselu APC

Oríṣun àwòrán, screenshot

“A le mu adikun ba bi ẹto abo se meyẹ ni awọn agbegbe kan ti ijọba ba pese ise fun awọn olugbe Kano”

“Mi o ti ri idi kan gbogi lati ya iru owo naa nitori gbese to wa lọrun ijọba Kano, wọn ti yanju rẹ tan.”

"Oniriru nnkan miiran lo sẹlẹ si awọn olugbe Kano ti o yẹ ki ijọba dojuko sugbọn owo ni wọn ya."

Awọn olugbe Kano pẹlu awọn ara oke okun ni wọn ti fẹhonuhan papaa julo lori ayelujara pẹ ki ijọba gbinyanju lati mojuto awọn nnkan pataki ni ipinlẹ naa papa julo ni agbegbe ti idagbasoke ko dẹ