Àwọn àwòrán tó jojú nígbèsè láti ibi ìsìn ìdúpẹ́ àyípadà ìṣèjọba ní Nàìjíríà

Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Àkọlé àwòrán, Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Igbakeji Aarẹ Naijiria, Ọjọgbọn Yẹmi Oṣinbajo pẹlu iyawo rẹ, Dọlapọ
Àkọlé àwòrán, Igbakeji Aarẹ Naijiria, Ọjọgbọn Yẹmi Oṣinbajo pẹlu iyawo rẹ, Dọlapọ
Olori ijọba ologun nigbakan ri, Ọgagun Yakubu Gowon n ki iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Rẹmi Tinubu
Àkọlé àwòrán, Olori ijọba ologun nigbakan ri, Ọgagun Yakubu Gowon n ki iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Rẹmi Tinubu
iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Rẹmi Tinubu gunlẹ si ile ijọsin apapọ Naijiria, National Ecumenical Center nilu Abuja
Àkọlé àwòrán, iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Rẹmi Tinubu gunlẹ si ile ijọsin apapọ Naijiria, National Ecumenical Center nilu Abuja fun isin ọ̀pẹ ṣaaju ayipada iṣejọba ti yoo waye lọjọ Aje.
ọkan lara awọn iranṣẹ Ọlọrun to wa nibi eto naa
Àkọlé àwòrán, ọkan lara awọn iranṣẹ Ọlọrun to wa nibi eto naa
Awọn eekan nibi eto naa, Ọgagun Yakubu Gowon ati aya rẹ, iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Rẹmi Tinubu, igbakeji aarẹ Yẹmi Osinbajo pẹlu iyawo rẹ, Dọlapọ.
Àkọlé àwòrán, Awọn eekan nibi eto naa, Ọgagun Yakubu Gowon ati aya rẹ, iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Rẹmi Tinubu, igbakeji aarẹ Yẹmi Osinbajo pẹlu iyawo rẹ, Dọlapọ.
Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Àkọlé àwòrán, Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Awọn akọrin lọlọkan o jọkan lo wa nibẹ
Àkọlé àwòrán, Awọn akọrin lọlọkan o jọkan lo wa nibẹ
Awọn akẹkọọ pẹlu ko gbẹyin
Àkọlé àwòrán, Awọn akẹkọọ pẹlu ko gbẹyin
Awọn onijo loriṣiriṣi pẹlu wa nibi eto isin idupẹ naa
Àkọlé àwòrán, Awọn onijo loriṣiriṣi pẹlu wa nibi eto isin idupẹ naa
Awọn obinrin lẹgbẹlẹgbẹ ati lọgbalọgba pẹlu wa nibẹ
Àkọlé àwòrán, Awọn obinrin lẹgbẹlẹgbẹ ati lọgbalọgba pẹlu wa nibẹ
Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Àkọlé àwòrán, Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Awọn akẹkọọ naa wa nibẹ
Àkọlé àwòrán, Awọn akẹkọọ naa wa nibẹ
Awọn alufaa lati ilẹ okeere pẹlu peju sibi eto naa
Àkọlé àwòrán, Awọn alufaa lati ilẹ okeere pẹlu peju sibi eto naa
Akọwe ijọba Naijiria, Boss Mustapha pẹlu iyawo rẹ
Àkọlé àwòrán, Akọwe ijọba NAijiria, Boss Mustapha pẹlu iyawo rẹ
Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Àkọlé àwòrán, Iyawo aarẹ ti ilu ṣẹṣẹ dibo yan, Olurẹmi Tinubu
Gomina ipinlẹ Edo tẹlẹ, Adams oshiomole ti oun pẹlu ti figbakan ri jẹ alaga ẹgbẹ oṣel;u APC naa wa sibi eto isin naa
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Edo tẹlẹ, Adams oshiomole ti oun pẹlu ti figbakan ri jẹ alaga ẹgbẹ oṣel;u APC naa wa sibi eto isin naa
Gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Kayọde Fayẹmi naa wa nibẹ
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Kayọde Fayẹmi naa wa nibẹ
Biṣọọbu agba Praise to waasu nibi eto isin naa
Àkọlé àwòrán, Biṣọọbu agba Praise to waasu nibi eto isin naa
Gomina ipinlẹ Ogun tẹlẹ, Gbenga Daniel naa wa nibẹ
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Ogun tẹlẹ, Gbenga Daniel naa wa nibẹ
Woli Esther Abimbola Ajayi ti ọpọ mọ si iya Adura naa wa sibi eto isin ọhun
Àkọlé àwòrán, Woli Esther Abimbola Ajayi ti ọpọ mọ si iya Adura naa wa sibi eto isin ọhun
Akọwe ẹgbẹ oṣelu APC Oloye Omiṣore pẹlu wa sibi eto naa
Àkọlé àwòrán, Akọwe ẹgbẹ oṣelu APC Oloye Omiṣore pẹlu wa sibi eto naa
Awọn olori ileeṣẹ ọmọogun ni NAijiria naa peju sibẹ
Àkọlé àwòrán, Awọn olori ileeṣẹ ọmọogun ni NAijiria naa peju sibẹ
Awọn eekan to peju sibi iṣẹ isin naa
Àkọlé àwòrán, Awọn eekan wa nibi eto naa