Orúkọ, àtàwọn nǹkan tí àwọn èèyàn wá jùlọ lórí Google nínú ọdún yìí rèé

Oríṣun àwòrán, others
Ileeṣẹ Google ti kede awọn nnkan ti awọn eeyan n wa julọ lori ikanni naa ninuọdun yii.
Oludije sipo Aarẹ ninu ẹgbẹ oṣelu Labour, Peter Obi, ẹrọ ilewọ iPhone 14, to fi mọ awọn olorin takasufe Oxlad ati Asake wa lara awọn eeyan ti wọn wa julọ lọdun 2022.
Lara awọn nnkan mii ti awọn eeyan tun n wa ni idije ife ẹyẹ Afrika, Afcon, iyanṣẹlodi ẹgbẹ awọn olukọ fasiti, ASUU, ati oṣere ọmọ ilẹ Amẹrika, Will Smith.
Eredi ti Peter Obi fi wa loke tente awọn ti awọn eeyan n wa ko ṣẹyin ọrọ “Obidient” to gbode lati igba ti oloṣelu naa ti kede pe oun fẹ du ipo Aarẹ.
Awọn eeyan tun n wa nipa iyanṣẹlodi ASUU latari bi awọn akẹkọọ ṣe joko sile kaakiria Naijiria, nigba ti awọn eeyan n wa nipa Will Smith lẹyin igbaju to bu lu adẹrinpoṣonu Chris Rock nibi ayẹyẹ ami ẹyẹ Oscar loṣu Kẹta ọdun yii.
Awọn nnkan ti awọn eeyan n wa ju lori Google lọdun 2022
- AFCON
- Iyanṣẹlodi ASUU
- IPhone 14
- Oxlade
- NATO
- Buga
- Peter Obi
- Ukraine
- Idije ife ẹyẹ agbaye World Cup
- Asake
Awọn eeyan ti awọn eeyan n wa ju
- Oxlade
- Peter Obi
- Asake
- Black Sheriff
- Casemiro
Awọn oṣere ti awọn eeyan wa ju
- Will Smith
- Johnny Depp
- Yul Edochie
- Osita Iheme
- Judy Austin
Awọn elere idaraya ti awọn eeyan n wa ju
- Casemiro
- Lisandro Martinez
- Antony
- Gabriel Jesus
- Raphinha
Akọsilẹ orin (lyrics)
- Finesse
- Overdise
- Rush
- If i broke na my business
- Palazzo
Bi wọn ṣe n se ounjẹ
- Bi wọn ṣe n se Fried Rice
- Ọbẹ Afang
- Bi wọn ṣe n se Jollof Rice
- Bi wọn ṣe n se burẹdi pẹlu ọgẹdẹ
- Parfait recipe
Ta ni..?
- Igbakeji Peter Obi
- Ta ni Ọbabinrin Elizabeth
- Ta ni ‘greek god of war’
- Ta ni oludije ẹgbẹ oṣelu APC
- Ta ni igbakeji Atiku
Ẹrọ ibaraẹnisọrọ
- Iphone 14 pro max
- Iphone 13 pro max
- Tecno Camon 19
- Infinix Note 12
- Tecno Spark 121
- Infinite Note 11
- Redmi Note 11
- Infinix Smart 6
- Tecno Spark 9
- Tecno Spark 8
Fiimu agbelewo
- Anikulapo
- Blood Sisters
- House of Dragon
- Thor - Love & Thunder
- The Woman King
- Selina Tested
- Tinder Swindler
- Black Panther 2
- Eternals
- All of us are dead
Orin
- Buga - Kizz Daniel
- Overdose - Mavin
- Machala - Berri Tiga ati Carter Efe
- Calm Down - Rema
- Rush - Ayra Starr
Awọn to jade laye
- Queen Elizabeth
- Osinachi Nwachukwu
- Ada Ameh
- Rico Swavey
- Takeoff
Awọn olorin
- Oxlade
- Asake
- Black Sherrif
- Portable
- Lil Tjay
Ki ni?
- Ki ni wọn n pe Lupus
- Ki ni NATO
- Ki ni NFT
- Ki ni eredi ogun laarin Russia ati Ukraine
- Ki ni itumọ Zazu Zeh
- Ki ni PVC
- Ki ni intersex
- Ki ni itumọ Sapa
- Ki ni wọn mọ Greta Thunberg si
- Ki ni awọn onimọ sayẹnsi n pe ‘ear ringing’








