Bí mo sͅe di oͅmoͅ Bola Tinubu rèé - MC Oluomo

MC Oluomo

Oríṣun àwòrán, kingmcoluomo/Instagram

Oͅpoͅloͅpoͅ awoͅn alatileͅyin kaakiri orileͅede Naijiria ni woͅn moͅ arakunrin MC Oluomo gͅgͅ bi oͅkan gboogi lara awoͅn alatileͅyin oludije sipo aareͅ leͅgbeͅ osͅelu APC, Bola Ahmed Tinubu.

Paapaa ko si eͅni to ba feͅ se opolongo idibo nipinleͅ Eko ti woͅn ki n wa ojurere MC Oluomo, bio tileͅ jeͅpeͅ owo ni woͅn feͅ loͅwoͅ reͅ tabi iranwoͅ nipa ipolongo ti woͅn feͅ sͅe.

MC oluomo to jeͅ adari eͅgbeͅ awakoͅ NURTW teͅleͅri lo sͅalaye irinajo reͅ peͅlu Asiwaju Bola Tinubu ati bi oun sͅe di oͅmoͅ reͅ timoͅtimoͅ.

Ninu ifoͅroͅweroͅ peͅlu ileesͅeͅ iroyin City People ni MC Oluomo ti sͅalaye bi o sͅe beͅreͅ irinajo reͅ lati kekere titi di asiko yii.

‘’Bi mo se di agbero’’

MC oluomo ni lati kekere ni awoͅn eniyan ti ma n woͅ teͅle oun paapaa ni igba ti oun beͅreͅ ileͅeͅkoͅ alakoͅbeͅreͅ

‘’Iya mi soͅfun mi wipe awoͅn oͅreͅ mi ni ileeͅkoͅ alakoͅbeͅreͅ ma n teͅleͅ mi wa si ile, to si jeͅ pe ile w ani woͅn ti ma n jeͅun oͅsan ki woͅn to pada loͅ si ile woͅn.’’

‘’Awoͅn oͅreͅ mi feͅran mi nigba naa ti a w ani ile iwe. Iya mi ma n ta jani agbegbe Opopona Oshodi ni ilu Abeokuta.’’

'Igba ti mo wa ni ipele keͅfa ni ileeͅkoͅ alakoͅbeͅreͅ ni o han gbangba pe iya mi ko lee san owo ileͅkoͅ mi moͅ , ti mo si beͅreͅ si ni sͅe agbero ni agbegbe Adatan.’’

''Ori bonnet oͅkoͅ ni a ma n kojo si nigba naa, ti mo si ma n ba awoͅn akeͅgbeͅ mi sͅere ni ileepoͅ Adatan, ti oͅpoͅloͅpoͅ ero yoo si joko yi mi ka’’

MC Oluomo

Oríṣun àwòrán, kingmcoluomo/Instagram

‘’Mi o fi eͅnu kan oti, siga tabi igbo ri lailai’’

‘’Bi o tileͅ jeͅpe igboro ni mod agba si, ohun kan ti mi o ki n se ni ki n ba woͅn mu oti lile tabi fa siga tabi lo oogun oloro.’’

‘’Titi di asiko yii, ohun ti mo ma n mu lasan ni omi ati maltina.’’

‘’Idi ti mi o ki fi n mu oti ni nitori iya mi. gbogbo igba ni mo ma n ranti reͅ nigba naa, ti aanu reͅ si ma n sͅe mi, mi o si feͅ ki ilakaka reͅ jasi asan lori mi.’’

‘’Bakan naa ni mi o ki n fi eͅsin eemarun oojoͅ sere rara, gbogbo igba ni mo ma n gbadura si Oͅlorun nitori igbagboͅ mi nipe , oun lo seͅ eͅda mi to si damisi ti oͅjoͅ oni.’’

MC Oluomo

Oríṣun àwòrán, kingmcoluomo/Instagram

"Ọrẹ baba mi ni Bola Tinubu, mo si maa n gbadura pe ko jẹ ọrẹ temi naa"

MC Oluomo ni o ti peͅ ti awoͅn ti n ba Asiwaju rin, ti ki n sͅe oͅroͅ oͅdun kan tabi oͅroͅ oͅdun meji.

‘’Asiwaju jeͅ enikan ti ko feͅran ki eniyan maa pa iroͅ, o feͅran olootoͅ eniyan.’’

‘’Nigba naa loͅhun to n dije du ipo seͅnetoͅ, omode ni wa, ti mo si wa ni agbegbe Oshodi nigba naa geͅgeͅ bi awakoͅ.’’

‘’Bakan naa nigba ti o n dije du ipo gomina nigba akoͅkoͅ, ti o si jͅẹ oͅreͅ baba mi ni mo ti moͅ o.’’

‘’Nigba naa loͅhun, adura mi nipe ki Asiwaju se alabapade mi, ki a si jeͅ oͅreͅ timoͅtimoͅ.

Nigba naa loͅhun, n se ni Tinubu ma n ju awo orin Ayinde sileͅ fun awoͅn eniyan ni oͅfeͅ, ti a o si maa sa teͅle ni eͅyin.’’

Àkọlé fídíò, Joy Adekunle Adejare: Torí òkìkí tí mo ní nídìí iṣẹ́ àgbo ni wọ́n ṣe jí ọkọ mí gbé, pa á

"Tinubu lo pe mi pada wa sile lati ilu oyinbo"

Bakan naa ni Oluomo fikun un pe Tinubu lo pe oun pada si Naijiria lati ilu London nigba naa loͅhun.

‘’Lati igba naa si ni mo si ti wa peͅlu Tinubu. Ko si ibi to ba n loͅ ti mio ki n teͅle, ti o si fi oͅkan tan mi.’’

MC Oluomo fikun un pe oun feͅran lati maa rin irinajo lati ibi kan si omiran paapaa lasiko igbafeͅ ati isinmi.

O sapejuwe awoͅn oͅmoͅ rͅeͅ geͅgeͅ bi awoͅn oͅmoͅ ‘butter’ ti oͅpoͅ ninu woͅn si w ani oke okun.

MC Oluomo ni ti awoͅn oͅmoͅ oun ba wa sile,inu ile ni woͅn ma n wa, ti woͅn si sunmoͅ iya woͅn ju oun loͅ.