''Ojú máa ń tì mí láti jáde nítorí ọmú aya mi''

Oríṣun àwòrán, KATIE SILVESTER
Itiju ati inira lo jẹ ọrọ meji ti obinrin le fi sọ iriri rẹ nitori pe o ni igbaya nla.
Jackie Adedeji ro pe awọn ko kọ bi ara si ni ni omu nla, ti pupọ si ri gẹgẹ ohun awada ni ilẹ UK.
O nini omu nla toto iwọn mẹrindinlogoji fẹ jẹ ko oun sapamọ ni awọn asiko kan ni igbesi aye rẹ.
“Lati ọmọ ọdun mọkanla ni mo ti dun lọmọbinrin. Mo ranti nigba ti mo wa ni ile ẹkọ, ti mo ba wọle bayi ni awọn ọkunrin, paapaa awọn agbalagba maa ma ji mi wo, ti wọn yoo si ma pọn awọn wọn la”
“Mo ti wa ni ipade, ti awọn akẹgbẹ mi ko si le gbe oju kuro lara mi, to si ma mu mi rope mo jẹ ohun ibalopọ”
Jackie se alaye awọn ọrọ lasiko to n kopa ninu isẹ iwadii, ‘Channel 4 documentry My Big Boobs:UNTOLD, o ni oun ti kọ lati maa ba omu nla oun gbe bi oun se n dagba si.

Oríṣun àwòrán, ACME PRODUCTIONS
Sugbọn ọpọlọpọ obinrin lo wa nita bayi, ti wọn sapamọ , to si ti wọpọ ni agbegbe wa.
Ajọ to n risi isẹ abẹ Aesthetic lorilẹede Gẹẹsi ni omu didikun ni isẹ abẹ keji to wọpọ julọ.
O ni isẹ abẹ toto ẹgbẹ marun un fun omu dindiku lowaye lọdun 2022.
Jackie ni oun ko rope awọn eeyan mọ bi nini omu to tobi se ma da ọpọlọ ru .
“Ohun itiju ni lo jẹ fun wọn nitori ọpọlọpọ eeyan lo ro pe awọn ni anfani si omu rẹ nigbati won ba ti tobi, wọn ma ri wọn gẹgẹ bi ẹrun ita”
Bakan lo ni bi oun se jẹ ọmọ to ti ile ẹlẹsin wa, ọpọ igba ni wọn fẹ ki oun mura ko bo ara oun.
“O yẹ ki eeyan dun lọmọi binrin, ati pe gẹgẹ bi ọmọ dudu, ọpọ igba ni mo salabapada ohun to da , ti mo ri ma ro pe omu igba aya mi kọ lo fa.”
‘Ẹ fi Obinrin naa silẹ’
Amber na ti wa ninu ẹsẹ bata yii, to si ni lati pinnu ni ibẹrẹ ọdun 2022 lati lọ foripam,ọ si ibi kan.
Lẹyinọpọlọpọ ọdun ninu irọnu and inira nitori ọmu rẹ to to mẹrindinlọgọta ni wiwọn, isẹ abẹ lo jẹ ohun ti obinrin, ọmọ ọdun mẹrindinlọgbọn to wa lati Cornwell ti fẹ se tipẹ.
“Lati igba ti mo ti kuro ni ile ẹkọ ni mo ti n la isoro yii kọja sugbọn lẹyin igba ti mo fun ọmọ mi lọmu mu, iniri yii de ibi kan to jẹ pe oun le rin lai ni irina.
Lakọkọ , o gbinyanju lati se isẹ abẹ labẹ NHS sugbọn wọn kọ lati ba se ni ọpọ igba.
“Emi ati ọkọ mi ni lati sọrọ, a si pinnu lati yawo”
“Pẹlu bi nnkan se ri lasiko naa, igbesẹ isẹ abẹ ọhun jẹ ohun inu mi dun si pipọ.”

Oríṣun àwòrán, Amber
Sise adikun si omu ko jẹ nnkan to nira lati se ni NHS , gẹgẹ bi ti awọn yooku, o jẹ ọjọ pipẹ.
Ẹnikan to ri isẹ abẹ NHS se is ọmọ ọdun mejidinlọgbọn, Rachael.
Sugbọn iyẹn waye lẹyin ọdun mẹwaa ti dẹkọ dokita pe ẹyin n ro oun ati bi awọn eyan kan se n fu se yẹyẹ pe ọmu rẹ tobi.
Racheal ni wọn sọ pe ko igbinyanju lati ru diẹ pẹlu bo se ni BML, asiko to ke sita pe oun ni ẹyin riro ni wọn gba gbọ.
“Mo gbinyanju lati lo ogun ara riro fu osu mẹfa kiu wọn to gba lati se isẹ abẹ fun mi, to si tuin gba mi lọdun meji si,”
Racheal ni oun ki ara ku orire pe oun ni anfani naa ati pe igbe si aye oun lẹyin isẹ abẹ ọhun dara gan.
“Ki n to se isẹ abẹ, n ko le saare lai ma ni inira. Eyi lo jẹ nnkan ti pọ gan.
“Ninu mi dun si ara mi ju ti tẹlẹ lọ,”

Oríṣun àwòrán, RACHAEL
Ki lo de ti awọn obinrin fi se dikun ọmu?
Igbakeji aarẹ BAAP Nora Nugent ni igbagbọ pe dindin ọmu jẹ nnkan to le mu irọnu wa, to si ọpọlọpọ anfani to se ara lore.
“O n se iranwọ nipa mu mu ara ji pepe, ti asọ yoo si se le se dada lara eeyan.”
Dokita isẹ abẹ ọhun ni oun gbagbọ pe dindin ọmu ko ki se ewọ mọ bi ti tẹlẹ.
“Fun igba pipẹsise isẹ abẹ ni ọpọlọpọ ohun asiri to dirọ mọ, ti awọn eeyan ko sọrọ nipa rẹ sugbọn bayii, o ti wa ni gbangba.”















