Oscars 2024: Wo orúkọ àwọn òṣeré fíìmù tó gba àmì ẹ̀yẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Awọn gbajugbaja oṣere ere tiata orileede Amẹrika to pegede ti gba ami ẹyẹ wọn nibi ayẹyẹ Oscars ọdun yi ni Los Angeles.
Eyi ni ẹkunrẹrẹ orukọ awọn to pegede ati awọn mii ti wọn yan nibi ami ẹyẹ naa.
Ami ẹyẹ fiimu to pegede
- Olujaweolubori: Oppenheimer
- American Fiction
- Anatomy of a Fall
- Barbie
- The Holdovers
- Killers of the Flower Moon
- Maestro
- Past Lives
- Poor Things
- The Zone of Interest
Ami ẹyẹ oṣerebinrin to pegede
- Olujaweolubori: Emma Stone - Poor Things
- Annette Bening - Nyad
- Lily Gladstone - Killers of the Flower Moon
- Sandra Huller - Anatomy of a Fall
- Carey Mulligan - Maestro
Ami ẹyẹ oṣerekunrin to pegede
- Olujaweolubori: Cillian Murphy - Oppenheimer
- Bradley Cooper - Maestro
- Colman Domingo - Rustin
- Paul Giamatti - The Holdovers
- Jeffrey Wright - American Fiction
Ami ẹyẹ oṣerebinrin to wa ni ipo alatilẹyin to pegede
- Olujaweolubori: Da'Vine Joy Randolph - The Holdovers
- Emily Blunt - Oppenheimer
- Danielle Brooks - The Color Purple
- America Ferrera - Barbie
- Jodie Foster - Nyad
Ami ẹyẹ oṣerekunrin to wa ni ipo alatilẹyin to pegede
- Olujaweolubori: Robert Downey Jr - Oppenheimer
- Sterling K Brown - American Fiction
- Robert De Niro - Killers of the Flower Moon
- Ryan Gosling - Barbie
- Mark Ruffalo - Poor Things

Oríṣun àwòrán, Reuters
Ami ẹyẹ oludari ere to pegede
- Olujaweolubori: Oppenheimer - Christopher Nolan
- Anatomy of a Fall - Justine Triet
- Killers of the Flower Moon - Martin Scorsese
- Poor Things - Yorgos Lanthimos
- The Zone of Interest - Jonathan Glazer
Ami ẹyẹ orin to pegede
- Olujaweolubori: Ki ni a da mi fun? - Barbie (Billie Eilish, Finneas O'Connell)
- The Fire Inside - Flamin' Hot (Diane Warren)
- I'm Just Ken - Barbie (Mark Ronson, Andrew Wyatt)
- It Never Went Away - American Symphony (Jon Batiste, Dan Wilson)
- Wahzhazhe (A Song For My People) - Killers of the Flower Moon (Scott George)
Ami ẹyẹ orin apilẹkọ fiimu to pegede
- Olujaweolubori: Oppenheimer
- American Fiction
- Indiana Jones and the Dial of Destiny
- Killers of the Flower Moon
- Poor Things

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí nipa Oscars

Best adapted screenplay
- Olujaweolubori: American Fiction
- Barbie
- Oppenheimer
- Poor Things
- The Zone of Interest
Best original screenplay
- Olujaweolubori Anatomy of a Fall
- The Holdovers
- Maestro
- May December
- Past Lives

Oríṣun àwòrán, Reuters
Best international feature
- Olujaweolubori: The Zone of Interest
- Io Capitano
- Perfect Days
- Society of the Snow
- The Teachers' Lounge
Best animated feature
- Olujaweolubori: The Boy and the Heron
- Elemental
- Nimona
- Robot Dreams
- Spider-Man: Across the Spider-Verse
Best documentary feature
- Olujaweolubori: 20 Days in Mariupol
- Bobi Wine: The People's President
- The Eternal Memory
- Four Daughters
- To Kill a Tiger
Best cinematography
- Olujaweolubori: Oppenheimer
- El Conde
- Killers of the Flower Moon
- Maestro
- Poor Things
Best sound
- Olujaweolubori: The Zone of Interest
- The Creator
- Maestro
- Mission: Impossible - Dead Reckoning Part One
- Oppenheimer
Best film editing
- Olujaweolubori: Oppenheimer
- Anatomy of a Fall
- The Holdovers
- Killers of the Flower Moon
- Poor Things
Best visual effects
- Olujaweolubori: Godzilla Minus One
- The Creator
- Guardians of the Galaxy Vol. 3
- Mission: Impossible - Dead Reckoning Part One
- Napoleon
Best costume design
- Olujaweolubori: Poor Things
- Barbie
- Killers of the Flower Moon
- Napoleon
- Oppenheimer
Best production design
- Olujaweoluborir: Poor Things
- Barbie
- Killers of the Flower Moon
- Napoleon
- Oppenheimer
Best make-up and hairstyling
- Olujaweolubori: Poor Things
- Golda
- Maestro
- Oppenheimer
- Society of the Snow
Best animated short
- Olujaweolubori War Is Over! Inspired by the Music of John & Yoko
- Letter to a Pig
- Ninety-Five Senses
- Our Uniform
- Pachyderme
Best documentary short
- Olujaweolubori: The Last Repair Shop
- The ABCs of Book Banning
- The Barber of Little Rock
- Island In Between
- Nǎi Nai and Wài Pó
Best live action short
- Olujaweolubori: The Wonderful Story of Henry Sugar
- The After
- Invincible
- Knight of Fortune
- Red, White and Blue









