Nigeria Oscars commitee : Ìdí tí sinimá Genevieve kò fi mókè ní Oscar Award

OSCAR

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM

Àkọlé àwòrán, Àjọ Alámì Ẹ̀yẹ Oscar ti fágilé fíímù tí gbajúgbajà Nollywood gbá jáde nítorí wọ́n se eré náà ní Ede Gẹẹsi.
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ajọ to n bojuto iyansipo fiimu ti yoo gba ami ẹyẹ Oscars lorilẹede Naijiria,NOSC ti kede wi pe lootọ ni fiimu Lionheart kuna awọ̀n agbekale Ami ẹyẹ Oscars.

Ajọ NOSC sọ eyi ninu atẹjade ti wọn fi lede lẹyin ti awọn ọmọ Naijiria bu ẹnu atẹ lu igbesẹ Oscars lati yọ fiimu naa kuro ninu awọn to n dije fun ami ẹyẹ Oscars.

Ajọ naa wa parọwa si awọn to n se fiimu lati ma a fi sọkan wi pe ti fiimu wọn ba fẹ gba ami ẹyẹ, o gbọdọ rọ mọ ofin ati ilana ki a gbe fiimu tabi cinema jade ni ede abinibi ti orilẹẹde Naijiria.

Bakan naa ni wọn fikun wi pe awọn ti kọ ọgbọn ninu ti ọdun yii, ti awọn si ni igbagbọ wi pe awọn yoo se daradara ni ọdun to n bọ ju ti ọtẹ yii lọ.

Wo ìdí tí Oscar fi fagilé Lionheart tí Genevieve gbé jáde!

Ajọ Alami Ẹyẹ Oscar ti fagile fiimu, Lionheart ti Naijiria yoo kọkọ fi silẹ lori atẹ Ami Ẹyẹ Oscar.

Ajo Oscars ni idi ti awọn fi fagile fiimu ti gbajugbaja oṣere Genevieve gbe jade yii ni wi pe ko si ni ede abinibi to wa lorilẹede Naijiria.

Genevieve nigba ti oun fesi si bi wọn se wọgile fiimu naa ni, ede Gẹẹsi ni ede apapọ awọn ọmọ Naijiria, nitori naa wọn ko lasẹ lati fagile iforukọsilẹ fiimu naa fun Ami ẹyẹ.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Bẹẹ ni awọn ẹlomiran bu ẹnu atẹ lu igbesẹ Oscar ti wọn si sọ wi pe iwa ẹlẹyamẹya ni nkan ti wọn n se.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Fiimu Lionheart naa ni Genevieve gbe jade, ti wọn sọ ede Gẹẹsi ati ede Igbo, amọ Ede Gẹẹsi ni wọn sọ ju ede Igbo lọ ninu rẹ.

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5

Lara awọn ofin to rọ mọ Ami Ẹye Oscar ni wi pe o gbọdọ jẹ fiimu ti wọn kọ ni ede abinibi, ti wọn pe orukọ ẹka Ami Ẹyẹ naa ni 'Best Foreign Language Film' .

Skip X post, 6
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 6