EMMY Awards 2018: Game of thrones gba àmì ẹ̀yẹ mẹ́jọ

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ni ọjọ Aje ni eto ifami-ẹyẹ-da awọn oniṣẹ ọpọlọ lẹka amuludun, orin ati ere sinima lọla (EMMY awards) waye ni ilu Los Angeles lorilẹ-ede Amẹrika.
Ere ọlọsọọsẹ 'Game of Thrones' lo gbayi julọ nibi ayẹyẹ naa pẹlu ami ẹyẹ mẹsan.
'Saturday live' pẹlu "The Marvelous Mrs Maisel" lo tun tẹlee pẹlu ami ẹyẹ mẹjọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Eyi si ni orukọ awọn to gba ami ẹyẹ nibẹ ati ami ẹyẹ ti wọn gba
Ere ọlọsọọsẹ to gbayi ju (OUTSTANDING DRAMA SERIES) : "Game of Thrones"

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ere apanilẹẹrin ọlọsọọsẹ (OUTSTANDING COMEDY SERIES) : "The Marvelous Mrs Maisel"
Oṣere akọkọ l'ọkunrin to pegede ju (BEST LEAD ACTOR, DRAMA): Matthew Rhys, "The Americans"

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Oṣere akọkọ l'obinrin to pegede ju (BEST LEAD ACTRESS, DRAMA) : Claire Foy, "The Crown"
Oṣere akọkọ l'ọkunrin to pegede ju ninu ere apanilẹrin (BEST LEAD ACTOR, COMEDY): Bill Hader, "Barry"

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Oṣere akọkọ l'obinrin to pegede ju ninu ere apanilẹrin (BEST LEAD ACTRESS, COMEDY) : Rachel Brosnahan, "The Marvelous Mrs Maisel"
Oṣere keji l'ọkunrin to pegede ju (BEST SUPPORTING ACTOR, DRAMA): Peter Dinklage, "Game of Thrones"

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Oṣere keji l'obinrin to pegede ju (BEST SUPPORTING ACTRESS, DRAMA): Thandie Newton, "Westworld"
Oṣere keji l'ọkunrin to pegede ju ninu ere apanilẹrin (BEST SUPPORTING ACTOR, COMEDY): Henry Winkler, "Barry"
Oṣere keji l'obinrin to pegede ju ninu ere apanilẹrin.














