Ekiti 2022: Kò sí ọlọ́pàá tó gbébọn ní ìbudó ìdìbò, A ti já gbogbo ẹ̀ṣọ́ Olóṣèlú kúrò lẹ́yìn wọn- Adejobi

Àkọlé fídíò, Ekiti 2022:Kò sí ọlapàá tó gbébọn ní ìbudó ìdìbò, A ti já gbogbo ẹ̀ṣọ́ Olóṣèlú kúrò lẹ́yìn

Oṣẹlu Ekiti ko kan agbofinro rara, aabo nikan ni a wa pese fun ara ilu- Adejobi

Oga agba fun ileeṣẹ ọlọpaa Naijiria to tun jẹ alukoro ileeṣẹ ọlọpaa Naijiria ba BBC sọrọ ní Ekiti.

Ifọrọwerọ naa lo ti sọ pe aabo ara ilu ni awọn ni lọkan fun ara Ekiti.

O ni oṣelu Ekiti ko kan agbofinro rara

Awọn ọlọpaa to gbebon yoo maa parooo kiri ni, wọn ko ni duro ni ibudo idibo kankan.