
Ekiti 2022: Wo ọ̀nà tí wà á gbà dé ibùdó ìdìbò rẹ̀ níbikíbi ni Ekiti

Oríṣun àwòrán, @INEC
Wo bi o ṣe le mọ ọna de ibudo idibo rẹ̀ nibikibi ni ipinle Ekiti laí daamu ara rẹ rara:
1) Wo kóòdù to wa lori kaadi idibo re: lápá òsì nibi ti awọran wa ni koodu naa wa fún ẹni tó ní kaadi ọlọjọ pipẹ (PVC), apa ọtun ni koodu naa wa fun eni ti ko ni kaadi ọlọjọ pipẹ ṣugbon to ni Temporary Voters Card (TVC)
2) Tẹ nọmba koodu naa si alafo to wa nisale yii.
3) Ki o wa waa pẹlu bọtini mo n waa (search button) ẹgbẹ ọtun
4) Lọgan ni wa a ri ibi ti o n lọ dibo.
- Wo àwọn nǹkan mẹ́wàá nípa olùdíje sípò gómìnà Ekiti lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party
- Ǹjẹ́ o mó Oladosu, ọmọ Peter Fatomilola tó jẹ́ olùdíje ẹgbẹ́ òṣèlú NNPP-
- Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Olaniyi Ben Agboola, olúdíje ẹgbẹ́ PRP nínú ìdìbò gómìnà ipinlẹ Ekiti
- Ajagunigbala Moses Olajide, pásítọ̀ tó fẹ́ di gómìnà ipinlẹ Ekiti lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ AAC
- Adájọ́ da ẹjọ́ Ilana Omo Oodua nu, tó ní kí wọn wọ́gilé ìbò gómìnà Ekiti àti Osun
- Ikọlù,APC, SDP Ekiti 2022- Èèyàn kàn kú,ẹgbẹ́ méjèèjì tako ará wọn









