Ayodeji Rotinwa ni ìròyìnn òfegè gbé àwòrán rẹ̀ síta pè dókítà tó ń pa àwọn Hausa mùsùlùmí
Ayodeji Rotinwa ni ọdọmokunrin kan ti aworan rẹ lu ori ayelujara pa laipe
Nibẹ ni wọn ti sọ pe oruko re ni Christopher Uche Ayodeji.
Leyin ti awọn alakatakiti ẹsin Islam kan dana sun Deborah Samuel to jẹ akẹkọọ ile ẹkọ olukoni Shehu Sagari ni ipinlẹ Sokoto ni iroyin naa jade.
- Àwọn òṣìṣẹ́ DSS gbìyànjú láti dóòlà Deborah, àmọ́ ọ̀pọ̀ èèrò borí wọn - Gómìnà Tambuwal
- Agbẹjọ́rò 34 táa tán nílé ẹjọ́, bí wọ́n ṣe sọ àwọn afurasí tó lọ́wọ́ nínú ikú Deborah Samuel sẹ́wọ̀n rèé
- Yorùbá ẹ fúnra, àwọn tó ṣekú pa Deborah fẹ́ dá ògún sílẹ̀ ni, wọn kò gbọdọ̀ lọ láì jìyà -Gani Adams
- Ẹ̀yin Òbí, ẹ fi ọmọbìnrin yin sílẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ tó wù wọ́n- Deborah tó ń fi ìlú bàtá àti gángan dárà
- Wo àwon ìròyìn òfégè nípa ikú Deborah Ṣamuel àti ìkọlù sí Bishop Kukah
- Ìjọba Sokoto kéde òfin kóníléógbélé lẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn lórí bí ọlọ́pàá mú àwọn tó pa Deborah Samuel
- Wo ibi ti ìgbẹ́jọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba méjì tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé wọ́n ji ọmọ arábìnrin tó ní arùn ọpọlọ gbé ní Akure
Ayodeji Rotinwa salaye pe oun ko tile sise dokita ri de ibi pe oun a nile iwosan lati fi maa pa awọn musulumi ti won wa lati eya hausa rara.
O ni akoroyin ni iṣẹ ori ran oun ti oun de n ṣelati ibẹrẹ aye oun titi di oni yi.
Ayodeji salaye pe lati igba naa ni oun ti sakuro nile to n gbe to si n sa asala fun emi ara rẹ latari iroyin ofege ti wọn pa mọ oun.