Explosion at OBJ Library: Ọ̀kan nínú àwọn méjì tí wọ́n gbe lọ ilé ìwòsàn ti dèrò ọ̀run

Oríṣun àwòrán, @SamuelOmogor
Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni yajoyajo ti fi ye ni pe eeyan meji ti dero ile iwosan nigba ti ẹrọ amuletutu, taa mọ si Air Conditioner bu gbamu.
Ọga agba kan nileesẹ naa to fidi isẹlẹ yii mulẹ fun BBC Yoruba salaye pe lootọ ni isẹlẹ naa waye amọ oun ko le sọ boya awọn eeyan meji to fara pa ti ku.
O fikun pe awọn eeyan mejeeji naa lo wa tun ẹrọ amuletutu naa se nigba ti afẹfẹ gaasi inu rẹ bu gbamu, to si se wọn lese.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìyàwó kẹrin gún ọkọ rẹ̀ lọ́bẹ pa torí ó fún obìnrin míì lóyún
- Yóò dára kí APC kópa nínú ìbò káńsù, kí ẹsín wọn lè hàn sí aráàlú - PDP
- Princess jèbùrẹ́, ọ̀rọ̀ Baba Ijesha gbóná ju èrò ọ̀pọ̀ èèyàn lọ - Adewale Eleso
- Yomi Fabiyi bá Sanwo-Olu, gómìnà Eko sọ̀rọ̀ lórí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha
- Àkúntúnkú, ìgbà mẹ́fà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ rè é tí Shekau kú, tí wọ́n ní kò kú mọ
- Ìrọ́ lẹ pa, ìbò ìjọba ìbílẹ̀ kò ní wáyé l‘Oyo ní Sátidé - APC fárígá
- Èèmọ̀ wọ̀lú! Àwọn jàndùkú jí Adájọ́ gbé lọ nínú kóòtù lọ́sàn án gangan
- Ẹ̀yin tí ẹ sọ pé irọ ni mo ń pa bayii ni yoo ri fún yín
"N ko si nibẹ nigba ti isẹlẹ naa waye, amọ ohun ti wọn sọ fun mi ni pe ọga kan ati ọmọ isẹ rẹ lo wa yẹ awọn ẹrọ AC wa wo.
Nigba to de ibudo kan, lo ri pe ọkan ninu awọn AC naa ni afẹfẹ gaasi rẹ n jo sita, o wa gbiyanjo lati fi ina jo, ko le di oju ibi to ti n jo sita.

Oríṣun àwòrán, Ben Murray Bruce
Boya o n jo lọwọ ni o, tabi igba to n fi gaasi naa sinu AC ni ibugbamu ọhun waye, n ko mọ nnkan to sẹlẹ, ti eyi fi waye.
O fikun pe wọn ti gbe awọn mejeeji lọ sile iwosan fun itọju amọ oun ko le sọ boya wsn si wa laye tabi wọn ti jẹ Ọlọrun nipe.








