Bed Wetting: Tolulope Joseph ní ò lé ní ogún ọdún tí òun fi tọ̀ sílé kí ìwòsàn tó dé
Iwa ki ọmọ maa tọ sile kii se ohun ajeji nilẹ Yoruba eyi to maa n ba obi ati iru ọmọ bẹẹ ninu jẹ lai tete ri ọna abayọ si aisan naa.
Ohun to sẹlẹ si Tolulope Joseph ree ẹni to n tọ sile titi di ẹni ọdun marundinlọgbọn.
Nigba to n salaye ọpọ idẹyẹsi ati idojuti to dojukọ nitori aisan tọle-tọle, Tolulope ni ọpọ asa abalaye ni oun tẹle lati wa ojutu si aisan naa.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Máṣe tijú láti gé ọmú rẹ to bá ṣàkíyèsí kóró nínú ọyàn, ilèra ló ṣe kókó - Ẹni tó ye àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn
- Àìsàn ìtọ̀ súgà kò túmọ̀ sí pé èèyàn ti gba ọjọ́ ikú- Dókítà Wilson
- Àwọn àmi méje tó ń tọ́ka sí pé oò kí ń mu omi bí ó ti tó
- Àlàyé rèé lórí ohun tí ìtọ̀ rẹ ń sọ nípa ìlera rẹ
- 82% ọkùnrin ní kó mọ̀ pé òun ní àìsàn jẹjẹrẹ asẹtọ ní Naijiria
- Wo àmì márùn-un tí o fi le mọ ẹni tó fẹ́ gbẹ̀mí ara rẹ̀
- A kú oríire! Oró agbọ́n leè wo àìsàn jẹjẹrẹ ọmú sàn, wo ohun tí wàá lò pọ̀ mọ́ra wọn
- Mi ó lè na apá mi àmọ́ mo lè lo ọpọlọ mi fí kọrin-Ayeyi
O ni oun maa n kunlẹ lati bẹ ọlọ ata ni alẹ, to fi mọ opo ina, ti oun yoo si tun tọ sinu ẹyin ina, ki oun ma baa tọ sile loru.
Amọ o ni pabo ni gbogbo awọn igbesẹ naa ja si titi di iwa ti oun ls ka nipa aisan naa lori ayelujara ti wọn n pe ni Enuresisi.
Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo ìgbẹ̀yìn àwọn ọlọ̀tẹ̀ Yorùbá tó ran Fulani lọ́wọ́ láti kógun ja ìlú Osogbo
- Ìtàn ìgbé ayé Bode Thomas rèé, ó kọ́ wa láti máa kó ẹnu wa ní ìjánu
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
- Ìtàn Àrọ̀gìdìgbà jẹ́ kí ń rò pé bàbá mi yan Yemọ̀ja ní àlè - Ọmọ Fagunwa
- Ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí Akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú Awolowo rè é
- Ìtàn Gbọnka àti Timi, akọni méjì tó borí Aláàfin Ṣango
- Wo ìṣẹ̀lẹ̀ márùn-ún tí kò bá pín Nàíjíríà sí yẹ́lẹ-yẹ̀lẹ
- Eji Gbadero, ọmọ Ibadan àti jayé-jayé ọmọ ónílẹ̀ ti wọn yẹgi fun l'Eko
Tolulope, to n sinru ilu lọwọ bayii ni ọna abayọ toun ri nipa ohun to n fa aisan tọletọle, ti oun si wa ojutu si, lo mu ki oun kọ iwe jade lati tọ awọn eeyan miran sọna.
A ṣe fidio yii pẹlu ifọwọsọpọ pẹlu Oyeyemi Gbenga-Mustapha.



