Urine Colour: Fídíò Lahanmi yìí ló ń ṣàlàyé nípa ọ̀pọ̀ àìsàǹ tó rọ̀ mọ́ bí ìtọ̀ wa ṣe rí

Àkọlé fídíò, Urine Colour: Fídíò Lahanmi yìí ló ń ṣàlàyé nípa ọ̀pọ̀ àìsàǹ tó rọ̀ mọ́ bí ìtọ̀ wa ṣe rí

Ọpọ aisan ni kii tete fi oju han ninu agọ ara titi ti yoo fi se ipalara.

Amọ itọ jẹ eroja kan pataki ti yoo tete pe akiyesi wa si aisan to ba wọle si agọ ara wa.

Ninu fidio yii ti BBC Yoruba se lati fi seto ilanilọyẹ fun araalu, lo n sọ awọn ohun to yẹ ka se akiyesi rẹ ninu itọ wa.

Eyi yoo si jẹ ka mọ irufẹ awọn aisan to rọ mọ irufẹ ayẹwo ti itọ wa n mu jade.

Ẹ wo fidio naa, lati kọ ọgbọn nipa ohun ti itọ rẹ n sọ nipa ilera rẹ.