Lassa Fever: Ìwádìí ní èèyàn 219 ni ibà Lassa pa lọ́dún tó lọ́, 29 lọ́dún yìí, tètè dènà rẹ̀

Lori eto Laahanmi ti BBC Yoruba, a se atupalẹ ohun ti iba Lassa jẹ, ọsẹ to n se lawujọ wa ati awọn ọna ta fi lee dena rẹ.
Fidio naa Laahanmi naa ree:
Iwadi fi ye wa pe awọn ekute ile lo n fa iba yii, eyi to n sekupa ọpọ eeyan lọwọlọwọ bayii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Okada Ban: ọjọ kini oṣù keji ni òfin tuńtun yóò bẹ̀rẹ̀
- Ẹ wo bí Amotekun ṣe gba ilẹ̀ Yoruba silẹ̀ lọ́wọ́ agbéṣùnmọ̀ní ní igba ọdún sẹ́yìn
- Tí ìjọbá bá kọ̀ láti san owó oṣù wa, a o da iṣẹ́ sílẹ̀ - ASUU
- Maryam Sanda, ìyàwó tó pa ọkọ rẹ, ri ìdájọ ikú he
- Wo ìgbésẹ̀ tó yẹ ko gbé tí kokoro bá ba irè oko rẹ jẹ́
Ẹ wo fidio yii lati mọ iye eeyan ti arun yii ti pa, awsn ohun to n sokunfa rẹ, ami ta fi mọ pe iba Lassa wa lara eeyan kan ati ọna ta lee gba dena rẹ.









