Flooding in Lagos: Ojú àwọn ará Èkó rí màbo pẹ̀lú òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá dá wàhálà sílẹ̀ ní Eko
Ko si ẹni ti kii gbadura fun ojo paapaajulọ fun itura bi oju ọjọ ba ṣe bi ẹni mooru.
Amọṣa fun awọn olugbe ipinlẹ Eko, ohun ti oju wọn ri, paapaajulọ awọn osiṣẹ to n lọ si ẹnu iẹ oojọ wọn, kọja sisọ.
Diẹ lara bi oju ọjọ ṣe ri kaakiri ree pẹlu aworan.













