Xenophobia: Ezekwesili ní bá ṣe yanjú ìkọlù South Africa ló fa sábàbí

Oríṣun àwòrán, @obyezeks
Minisita tẹlẹ ri lorilẹ́ede Naijiria,Obby Ezekwesili ti mu alaye bẹnu lori oun to mu lọ kopa ninu ijiroro agbaye lori ọrọ aje to n waye ni South Africa.
Ezekwesili ṣalaye ọrọ yii loju opo Twitter, toun ti bi awọn ọmọ Naijiria kan ṣe n bẹnu atẹ́ lu pe ko yẹ ko lọ nitori ikọlu Xenophobia to n ṣẹlẹ.
Saaju ni ijọba Naijiria ti kede pe, awọn ko nikopa ninu apero naa ti awọn ilumọọka olorin kan naa si ti ni awọn wọgile lilọ si South Afrika lati lọ ṣere.
Ninu ọrọ rẹ Ezekwesili ni oun yoo lo anfaani kikopa ninu apero naa lati daba awọn nkan to yẹ ki ijọba South Afrika ṣe lori isẹlẹ ikọlu sawọn ajeji.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Ajafẹtọmọniyan naa tun tẹsiwaju pe, ko yẹ ki orileede South Africa sa si abẹ ika pe o n gbalejo apero agbaye lai ṣe pe wọn fi ijiya to tọ jẹ.
Amọ ṣa, igbesẹ Ezekwesili yi mu ariwisi ọtọọtọ wa laarin awọn ọmọ Naijiria. bi awọn kan ṣe n gbosuba fun, lawọn miran n bẹnu atẹ lu
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4

End of X post, 5
Koda, Bashir Ahmad to jẹ oluranlọwọ aarẹ Buhari wa lara awọn to sọ oko ọrọ si Ezekwesili.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 6
Ọrọ naa fẹ ṣe bi itahunsiaraẹni laarin awọn mejeeji yii.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 7

End of X post, 8
Ibi ti ọrọ naa yoo kangun si ko ti yewa, ṣugbọn eyi to daju ni pe ijọba Naijiria ni, South Africa ti ba doju ẹ ati pe, awọn ko ni mu ni kekere pẹlu wọn.
Yatọ si pe o kọ lati kopa ni apero ọrọ aje to n waye naa, Naijiria tun ti ni ki aṣoju rẹ nilẹ South Africa pada wa sile.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Kaakiri awọn ilu bi Eko, Ibadan, Uyo ati Abuja ni awọn ọmọ Naijiria ti n fi ẹhonu han lori iṣẹlẹ ikọlu ọhun, ti awọn kan si n ba ileeṣẹ ti wọn fura si pe o jẹ ti awọn ọmọ South Africa jẹ.