Xenophophia: Lizzy Anjorin, Yinka Ayefele, Mercy Aigbe sọ̀rọ̀ ìtùnú

Yinka Ayefele, Lizzy Anjorin, Woli Agba ati Mercy Aigbe
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Ọrọ ikọlu ti awọn ọmọ Naijiria to wa lorilẹede South Africa n koju ati iwa igbẹsan to tẹle lati ọdọ awọn ọmọ Naijiria ti n ta ọpọ eeyan lara.

Lara awọn eeyan to n gbarata lori bi wọn se n se awọn ọmọ Naijiria ni isekuse ni South Africa ni awọn gbajumọ ati ilu mọọka lawujọ, to fi mọ awọn osere tiata.

Bakan naa ni awọn eekan ilu yii tun n rawọ ẹbẹ sawọn ọmọ Naijiria to n gbẹsan ikọlu ọhun lara awọn eeyan ati ileesẹ to jẹ ti ọmọ ilẹ South Africa to wa ni Naijiria pe, ki wọn bomi suuru mu nitori aforo yaro kii jẹ ki oro tan.

Loju opo Twitter, Instagram ati Facebook si ti kun fun ọpọ awọn ilumọọka yii ti wọn ko kawọ gbera lori isẹlẹ to n waye naa yika orilẹede Naijiria ati ni South Africa.

Ibudo itaja kan ti wọn ba jẹ

Loju opo Instagram rẹ, osere tiata lobinrin, Lizzy Anjọrin, ẹni to han loju rẹ pe inu rẹ ko dun si isẹlẹ naa, lo n kesi awọn ọmọ Naijiria pe ki wọn mase gbẹsan ikọlu awọn ara South Africa naa nitori awa ara wa ni ọrọ yii yoo kan julọ.

Skip Instagram post, 1
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 1

Bakan naa ni Yinka Ayefẹlẹ, tii se akọrin ẹmi ati sọrọsọrọ lori redio salaye pe iwa igbẹsan tawọn ọmọ Naijiria n se gbọdọ wa sopin nitori ohun ti ko dara, ko dara.

Skip Instagram post, 2
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 2

Nkechi Blessing Sunday, toun naa jẹ osere tiata Yoruba naa n rawọ ẹbẹ sawọn ọmọ Naijiria pe iwa ka jo ile itaja, ka ba dukia jẹ kọ ni ọna wiwa ojutu si ikọlu to n waye ni South Africa nitori ara wa la n pa.

Skip Instagram post, 3
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 3

Se ni Funke Etti naa n tara poro pe iru ki ni eyi, to si n rọ aarẹ Buhari lati tete dẹkun bi wọn se n pa awọn ọmọ Naijiria ni South Africa.

Skip Instagram post, 4
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 4

Ayọ Ajewọle, adẹrinposonu ti gbogbo eeyan mọ si Wolii Agba naa ko kẹyin ninu awọn gbajumọ to sọrọ sita tako ikọlu naa.

Oun naa ni ko dara to bi ijọba Naijiria ba bu ẹẹkẹ diwọ nipa bi wọn se n kọlu awọn ọmọ Naijiria ni South Africa, to si n rọ awọn alasẹ wa lati tete sọrọ sita.

Skip Instagram post, 5
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 5

Mercy Aigbe, tii se osere tiata lobinrin naa kesi awọn alawọ dudu lati yee kọju ija si ara wọn nitori iwa ailaju gbaa ni eyi.

Skip Instagram post, 6
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 6