Buhari gbọ́dọ̀ yọ àwọn mínísítà tí kò wúlò ní sáà kejì yí-Ogundamisi

Àkọlé fídíò, Buhari gbọ́dọ̀ yọ àwọn mínísítà tí kò wúlò ní sáà kejì yí-Ogundamisi

Lori ifilọlẹ saa isejọba to n bọ, onwoye nipa ohun to n lọ lawujọ naa ni Buhari yẹ ko yọ awọn oloye rẹ ti ko ba sisẹ bo se yẹ nipo, ko si fi awọn eeyan to da loju pe wọn yoo sisẹ kara sipo.

Ogundamisi tun ni isẹ ti isejọba Buhari se laarin ọdun mẹrin pọ pupọ, amọ iroyin ati ipolongo nipa awọn akanse isẹ naa mẹhẹ pupọ.

Kayọde Ogundamisi ni iṣejọba yii a so eso idagbasoke to yẹ ti aarẹ Buhari ba tete n gbe igbesẹ akin lori ọrọ awọn to n yan sipo laisko.