Arm forces Remeberance day: Naijiria ń ṣe ìrántí àwọn ológun to ṣubú lójú ogun

Awọn ọmọ ogun Naijiria to ti lọ

Oríṣun àwòrán, SODIQ ADELAKUN/AFP/Getty Images

Àkọlé àwòrán, ọpọ ọmọ ogun Naijiria lo ti fẹmi wọn silẹ
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Òní ni àyájọ́ ọjọ́ àwọn ọmọ ogun tói ṣègbé sójú ogun ní Naijiria, àwọn àwọran bí iranti naa ṣe ń lọ ati oun ti àwọn ọmọ Naijria n sọ rèé.

Àwọn ẹgbégun Naijiria gbalejo Aarẹ Muhammadu Buhari ni Eagles Square fun ayajọ ọjọ naa.

Eagles Square nibi ti awọn ọmọ ogun ti n ranti akegbe wọn ni ọjọ Isegun

Oríṣun àwòrán, Bashir Ahmad

Àkọlé àwòrán, Iṣe ologun buyi kun eniyan lawujọ

Buhari naa yan bi oloogun gẹgẹ bii olori ogun Naijiria.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Aarẹ Ile Igbimọ Aṣofin Agba Bukola Saraki ati abẹnugan Ile Igbimọ Aṣofin Kekere, Yakubu Dogara, naa juba awọn ọmọ ogun to ti ṣegbe ni Eagles Square.

Olori ile asofin Naijiria mejeeji, Bukola Saraki ati Yakubu Dogara

Oríṣun àwòrán, Bukola Saraki

Àkọlé àwòrán, Awọn oloṣelu gan mọ riri awọn ọmọ ogun

Saraki gbori yin fun awọn obirin ati ọkunrin to n fi ẹmi wọn daabo bo ọmọ Naijiria.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Gomina Ipinlẹ Kaduna, Nasir el-Rufai na ko gbẹyin. O sẹ ẹyẹ fun awọn ọmọ ogun to ti re kọja naa.

Gomina Ipinlẹ Kano, Nasir Elrufa

Oríṣun àwòrán, NASIR EL RUFAI

Àkọlé àwòrán, Aabo ẹmi ati adukia ara ilu lo jẹ wọn logun
Àkọlé fídíò, 2019 Elections: Aago mẹ́sàn-án àárọ̀ ni ìjíròrò Eko yóò bẹ̀rẹ̀

Ni Ipinlẹ Delta, Gomina Ifeanyi Okowa naa ṣe iranti awọn ọmọ ogun.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Àwọn oludije fun ipo Aarẹ bii Oby Ezekwesili na ṣe sàdáńkátà sí àwọn ọmọ oloogun.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: