Imam Fuad Adeyemi: Mọ̀wádà - Ìfẹ́ òtítọ́ gbudọ̀ wà nínú ìgbéyàwó
Ọ̀rọ̀ lori iwa ipá ninu ididle lo gbe BBC wa agba ọ̀jẹ̀ Imaamu lọ́ pe kini Kurani sọ nipa rẹ̀?
Ìwà ipá nínú ilé ti rìn jìnà gẹ́gẹ́ bíi kòkòrò ajẹnirun tó ti ń tú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé ká. Ṣùgbọ́n àwọn onímọ̀ ẹ̀sìn sọ pé ohun àá ṣeé ṣì kù.
O ni igbesẹ ti lọkọlaya yẹ ki wọn gbe ninu Islam tile ba fẹ maa daru.
Imam Fuad Adeyemi ti Mosalasi nla rẹ̀ wa ni Abuja to je olu ilu Naijiria salaye kikun lori koko yii
Imam Fuad Adeyemi ti mọṣalaṣi Al-Islabiyah sọrọ ni kikun lori ohun ti Islam faaye gba fun alaafia lati jọba ninu ile.
