Tawfiq Akinwale: Mo ni ìrírí tó pọ̀ pẹ̀lú ìbẹ̀rù Olúwa láti tukọ̀ ìpínlẹ̀ Oyo láàijẹ gbèsè mọ́

Àkọlé fídíò, Tawfiq Akinwale: Mo ni ìrírí tó pọ̀ pẹ̀lú ìbẹ̀rù Olúwa láti tukọ̀ ìpínlẹ̀ Oyo

Tawfiq Akinwale sọ pe ki awọn eeyan ipinlẹ Oyo maa wo akọsẹjaye awọn oludije ki wọn to dibo fun wọn.

Oludije labẹ ẹgbẹ oṣelu Labour Party nipinle Oyo, Ogbeni Tawfiq Akinwamle sọrọ ilẹ kun ninu ipade itagbangab ti BBC pe nipinle Oyo.

Nibẹ lo ti mẹnuba awọn nkan to ni lokan lati se to ba wọle si ipo gomina nipinle Oyo.

Akinwale sọ nipa iriri to ni alti koju iṣoro eto aabo ati ti eto ẹkọ nipinlẹ Oyo lasiko yii.

O sọ ero ọkan rẹ lori gbese tijọba ipinlẹ Oyo n jẹ bayii