Oba Adeyeye Ogunwusi: Tó bá tó àsìkò pé kí ìdí ṣu, ìdí á là ní ọ̀rọ̀ aya tuntun lọ̀ọ́dẹ̀ mi
Níbo lẹ́ ti gbọ́ pé Olorì míì ti wọ aàfin mi?- Ooni Ile Ife
Lori ọrọ pe Olori Naomi Silekunola yari laafin Oba Adeyeye Ogunwusi yii naa la ṣi wa.Olòrì Silekunola Naomi Ogunwusi: Mo ti sún síwájú, mo gbìyànjú pé kí ìgbèyàwó yìí ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n....
Eyi lo mu ki BBC Yoruba ranti diẹ lara awọn ileri ati adura ati ọrọ ijinle ti tọkọtaya ti sọ fun ara wọn loju araye sẹyinKí ló dé tí Ooni Ile Ife fẹ́ gbẹ̀mí ara rẹ̀?
Ninu ifọrọwerọ kan pẹlu BBC Yoruba loṣu to kẹwaa ọdun yii ni Kabiesi ti sọrọ lori aya tuntun lọóde wọn
- Alaafin ìlú Oyo gba adé lórí babalawo tó pe ara rẹ lọ́ba, ó fi adé náà kọ́ igi
- Àìsàn tó ń ṣe ọ ní ohun ṣe pẹlú oorun rẹ - Onímọ
- Ibi tí o bá dágbére fún ẹbí àti ará ní kí wọ́n ti ba ọ lásìkò ọdún Kérésì yìí- Akọ́ṣẹ́mọ́ṣẹ́ Bolarinwa
- A ti yí orin ọdún ń lọ sópin sí èdè Igbo àti Hausa - Mama Fasoyin
- Kóníléógbélé Covid 19 ló jẹ́ ká ronú gbé 'Learn Am' jáde láti ran àwọn ọmọ Nàìjíríà lọ́wọ́
Oba Adeyeye Ogunwusi ni pe: Ti asiko ba to lori aya tuntun, gbogbo re yoo han sita.
Saaju naa si ni Olori Naomi Silekunola ti gbadura fun Kabiesi pe owo, ọmọ alaafia ati aya a maa pọ si laafin.
- Ìjọba Osun jáwe lọ rọọ́kún nílé fún olùkọ̀ nítorí pé ó sọ̀rọ̀ tako ìjọba lórí Facebook
- Mọ̀ síi nípa Bola Ige tó jẹ́ mínístà ètò ìdájọ́ ṣùgbọ́n tí wọ́n ṣì ń wá ìdájọ́ òdòdo lórí ikú rẹ̀
- Kí ló dé tí Hisbah Kano ṣe fìwé pe Òbí Shatu Garko tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jẹ 'Miss Nigeria'?
- Ìjọba àpapọ̀ kéde ọjọ́ Aje àti ọjọ́ Iṣẹgun tó ń bọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ìsinmi ọdún Keresimesi
- Alaafin ìlú Oyo gba adé lórí babalawo tó pe ara rẹ lọ́ba, ó fi adé náà kọ́ igi
Koda, Olori Naomi pe akiyesi awon eeyan si i pe inu Oba dun pupo si adura naa.
O tun ni ki wọn ba oun dupe lowo Kabiesi pe Oba gba Olori bi o ṣe ri.
Oba Ile Ife naa dẹ ni ko si laburu ni aafin wọn nigba ti BBC beere nipa ahesọ edeaiyede laafin ni asiko ifọrọwanilẹnuwo naa loṣu kéwaa ọdun yii.


