Ijaw Paternity test: Mọ́ síi nípa ìgbàgbọ́ àwọn Ilaje nípa ọmọ ọkọ àti ọmọ àlè
Airinjinna ni airi abukẹ ọkẹrẹ.....
E wo idi ti awọn ara Ilajẹ Ese Odo ṣe n fẹ mọ ọmọ ọkọ yatọ si ọmọ ale ninu awọn ọmọ wọn.
Oloye Mercy Tanseni, to jẹ olukọ ni Bolowo, Opuba Arogbo ni Ilaje Ese Odo ba BBC sọrọ.
O salaye awọn igbesẹ ọmọ wiwẹ ni Ilajẹ.
- Àwọn Bòròró agbébọn ló pa Fulani ọmọ mi, a kọlù wọ́n lá fi rí eèyàn méjì gbà nínú àwọn tí wọ́n jígbé ní Ajowa-Baba Fulani
- Kò sí ẹni tí mo fura sí lórí ikú ọkọ mi, àmọ́...- Adebisi aya Titus Ejanla tí wọ́n pa ní Ibadan
- Mo fẹ́ kí a dá Yorùbá Nations sílẹ̀ kí a lè máa mójútó àwọn adarí tó bá kọsẹ́ fúnra wa- Peter Fatomilola
- Ẹlẹ́hà tó ń ró aṣọ tí kò bo ìdí rẹ̀ kìí ṣe aya ti wa ní Ilorin- Batimoluwasi Oníwákà
- Gọngọ́ sọ, àwọn Ṣọ́jà lé ọlọ́pàá lùgbẹ́ lágọ́ ọlọ́pàá l' Osogbo
- Ọmọ ọdún méje ni mo ti ń digunjalè, ogun ìdílé ló fàá, afurasí ṣàlàyé l'Ondo