Kidnap in Northern Nigeria: Àṣírí ìdí tí ìjínigbé fi ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà ló tú nínú fídíò
Kii ṣe iroyin tuntun mọ bayii pe awọn agbebọn n ji awọn agbebọn gbe ni iha Ariwa orilẹede Naijiria amọ laipẹ yii, o tilẹ ti n di lemọ lemọ.
Awọn nkan to foju han nipa ijinigbe yii ni pe wọn saba maa n lọ si ileewe. Bii ki wọn jo o kanlẹ tabi ba nkan jẹ ki wọn le raye wọle si wọn lara lati ri awọn eeyan jigbe.
- Bí Joe àti Yinka Odumakin ṣe pàdé lọ́gbà ẹ̀wọ̀n ti wọ́n sì fẹ́ra wọn láyé Abacha
- Sé Boko Haram ń pẹ̀ka kiri Nàíjíríà ní ìjínigbé ṣe burú báyìí?
- Wo ìgbà mẹ́rin táwọn agbébọn ti jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé nílé ẹ̀kọ́ wọn ní Nàìjíríà
- Buhari, ààwẹ̀ gbígbà ṣú ọmọ Nàíjíríà, jọ̀ọ́ ṣètò ìdẹ̀rùn - Tinubu lọgun
- Ọlọ́pàá Oyo n wa afurasí tó ṣekú pa oníṣòwò àti ọmọ ọdún mẹ́sán án méjì ní Ibarapa
Ibẹru bojo ti wa kaakiri ti awọn eeyan si n gbe e sọkan pe ikọlu naa yoo tun pọ si i.
Ninu fidio yii, alaye ẹkunrẹrẹ wa nibẹ nipa asiko to bẹrẹ, agbegbe to wọpọ si ati awọn nkan to ṣeeṣe ko ṣokunfa rẹ.