Bunmi Opakunle Car Wash: 'Slay Mama' ni mí; mò dẹ̀ tún ń fọ mọ́tò tà
Bunmi Opakunle to jẹ oludasilẹ ile iṣẹ to n fọ ọkọ ati ile, Mobile Wash ba BBC sọrọ lori irinajo aye rẹ ati ohun to sọọ di ẹni to n fọ ọkọ.
O mẹnuba awọn ọmọ iṣẹ to ni lọkunrin ati lobinrin ati awọn ipenija wọn.
- Kí ló fa ìjà rọ̀fọ̀rọ́fọ̀ láàrin Toyin Abraham àti olólùfẹ́ rẹ̀ lórí ayélujára?
- Ọ̀pọ̀ ọmọ Yorùbá ń ṣèdárò Yinka Odumakin tó di olóògbé
- Mo kọ láti gba lẹtà ọgá ọlọpàá, kí wọn má fi bọǹbù pa mí bíi Dele Giwa - Igboho
- Ẹkún àti ìdárò gbòde bí ọja páàtì ní Agodi-Gate ní Ibadan ṣe jóná mọ́jú
- Àwọn ọ̀nà tá gbà rèé tí orílẹ̀èdè Oduduwa yóò fi tẹ̀ wá lọ́wọ́ - Gani Adams
- Ọ̀daràn darandaran pàdà sí Igangan, wọ́n gé ọwọ ọ̀gá ilé ẹ̀kọ́
Bunmi Opakunle ti ọpọ maa n pe ni 'slay Mama' gba awọn ọdọ Naijiria ni imọran lati ma ro pe oke okun nikan ni ayọ wa bikoṣe pe ki wọn fi ọwọ ara wọn ṣiṣẹ\aje bi o ti yẹ.
Slay Mama sọ bo ṣe n ṣiṣẹ alase ounjẹ pẹlu ọkọ ati ile fifọ nitori pe ọna kan ko wọ ọja nigabgbọ awọn baba nla Yoruba.