Oluwatoyin Olanipekun: Wo àwọn òyìnbó tó ń kẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá ní Michigan, America
Iṣesi ati iwa àwon ọdọ Naijiria to wa ni America fihan pe iṣẹ m bẹ lọwọ awọn Olukọ- Oluwatoyin Olanipekun.
BBC Yoruba ko fẹ ki ede ati aṣa Yoruba parun kaakiri agbaye lo jẹ ki a gbe oju ọkan lara awọn ọmọ Oodua to n gbe aṣa ati ede Yoruba larugẹ nilẹ okeere wa fun un yin lonii.
Oluwatoyin Olanipekun to jẹ akẹkọọ-jade fasiti Obafemi Awolowo ni Ile Ife Oodua nibi ti ojumọ ti n mọ waye lo ba BBC sọrọ ni kikun lonii.
O salaye nipa awọn akẹkọọ rẹ to jẹ oyinbo ṣugbọn ti n wọn n kọ nipa ede Yoruba ni fasiti ipinlẹ Michigan ni orilẹ-ede America.
- 53712017Ìwà Bashorun Gaa ni Obaseki hù ní ipínlẹ̀ Edo -Tinubu
- Wo ohun tí Adájọ́ ṣe sí àṣùwọ̀n ìfowópamọ́sí Wòlíì Sotitobire
- Ìtàn ayé Shina Rambo, adigunjale tó fi oyún 27 gún ọṣẹ
- Wo àwọn àìsàn ti ìwọ́ ọmọ tuntun le wòsàn
- Afárá Third mainland gba ẹ̀gbọ́n
- Àwọn olè ń ṣọṣẹ nínú súnkẹrẹ-fàkẹrẹ ọkọ̀ tó ń wáyé nítorí afárá 3rd Mainland tí ìjọba tì
Oluwatoyin gba awọn Obi ati alagbatọ nimọran lati kọ awọn ọmọ wọn ni ede ati aṣa Yoruba lẹyin to ṣafihan awọn oyinbo to n sọ Yoruba lẹnu nibẹ.
O tun rọ awon ọdọ lati ni ifọkansin pẹlu igbiyanju nipa ọjọ ọla wọn.
- Báwo ni ìlù gángan se bẹ̀rẹ̀?
- Ọwọ́ tẹ àwọn ọlọ́pàá tó fìyà jẹ obìnrin kan lọ́nà àìtọ́ n'Ibadan
- Ọlọ́pàá kan sọ pé òun ní láti ṣàyẹ̀wò ìlédíìí ǹkan oṣù Arabìnrin kan kó tó lè kọjá
- Obìnrin àti ọmọdé tó há sábẹ́ ilé tó wó ní Ebute Meta ti ń gba ìtọ́jú, LASEMA ń ṣàyẹ̀wò ilé náà lọ́wọ́
- Kí ní 'Economy' ní èdè Yorùbá?
- Ò kéré tán N1million là ń ná lórí alárùn Coronavirus kọ̀ọ̀kan; àlàyé rèé- Ìjọba Eko