Coronavirus: Kínni ìtàkùn ayélujára 5G nííṣe gan na pẹ̀lú ààrùn coronavirus?
Ọpọ eeyan kaakiri agbaye papaa julọ lorilẹede Naijiria lo n gbe ahesọ ọrọ kan kiri pe itakun ayelujara 5G n ṣokunfa aarun coronavirus.
Amọ, ajọ eleto ilera lagbaaye, WHO ti ṣalaye pe itakun agbaye 5G ko lagbara to bẹẹ to fi le wọn inu ara eniyan lati fa aarun covid-19.
Ẹ maa gbagbe pe itakun ayelujara 5G n lo afẹfẹ lati mu igbayegbadun awọn eeuan to ba n lo ẹrọ ibanisọrọ.
BBC Yoruba ṣe alaye lẹkunrẹrẹ lori itakun ayelujara 5G.
- Wo àwọn ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa àrùn Coronavirus àti ìbálòpọ̀ akọ àt'abo
- Bẹ́mídíje ni mí, mo kọjá ẹni tí Coronavirus lè fi ta'yín- Ṣeyi Makinde
- Kí ló pa bàbá Adeboye, bàbá Davido àti Ọ̀ọ̀ni Ifẹ̀ pọ̀ lásìkò ìgbélé l'Ọ́ṣun?
- Máfọ́ya, mo wà pẹ̀lú ẹ, Ajimọbi kàn sí Makinde lóri Coronavirus to ni
- Coronavirus: Àwọn ohun tí a kò tíì mọ̀ nípa àrùn Covid-19
- Ibi gbogbo là ń dáná alẹ́, ìwà jẹgúdújẹrá pa iléeṣẹ́ Spencom run ní Uganda
- Iṣẹ́ bẹ̀rẹ̀! Seyi Makinde fojú hàn n'íta lẹ́yìn tó ṣẹ́gun Coronavirus
- Màmá Guardiola d'olóògbé lẹ́yìn tó lùgbàdì Coronavirus