Àrùn Coronavirus àti ìbálòpọ̀ akọ àt'abo: Wo àwọn ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Tí Mo ba ní ìbálòpọ̀ njẹ mo lè kó aarun Koronafairọs? Irú èrò yìí lè wa si yín lọ́kàn sugbon o tini lójú láti béèrè.Kí a yọ epo kúrò nínú àlìkámà, a ti bere ìbéèrè lowo awon onímò.Dókítà Alex George to je oníṣègùn oyinbo àti Alix Fox tó jẹ́ akoroyin nípa ìbálòpọ̀ to sì tún jé sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ lórí Radio BBC tí ṣàlàyé lórí àwọn ìbéèrè yìí.
Ṣe ko si ewu láti ni ìbálòpọ̀ lásìkò Coronavirus yìí?Dókítà Alex George: Bí ó bá ní olólùfẹ́, tí ẹ jọ ń gbé tí ẹ sì jó ń ṣe pò ni agbègbè kan náà, èyí kò yẹ kí o yí onkohun padà. Èwe tí a bá wà rí pé enikan ń fi àmì hàn èyí túmọ̀ sí pé kí ó fún ẹni náà láàyè tí oloyinbo ń pè ní Social Distancing kí ẹni náà sì wà ní igbele laarin ilé yín náà ni, ní ìlànà tó kofin ja ó yẹ kí olúkúlùkù máa fún ara wọn ní ààyè ìwọ̀n mita méjì sí ara ẹni,sugbon a rí pé èyí lè nira díè.Alix Fox: ó sì pọn dandan kí a mo pe bí ìwọ bá ní aarun náà tí ó sì àwọn àmì tí kò nira, má ro pe bẹẹ naa ni yoo ri fún enikeji rẹ, bí ó bá ti rí àpẹẹrẹ, yẹra fún olólùfẹ́ rẹ.

Tí Mo ba fi ẹnu kò ẹni tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ pàdé lenu tí ó wà padà rí àpẹẹrẹ aarun náà, kini kí n ṣe?
Doctor Alex: Bí ó bá fi ẹnu kò ènìyàn lenu, tàbí salabapade ẹni tí ó ní aarun náà, ri dájú pé o di ara rẹ sí igbele.Fojú àti ọkàn sí láti mọ bóyá ó ní àpẹẹrẹ, tí ó bá wà tí fi idi rẹ múlè pé ó ní aarun náà, ó jí láti sọra ṣe kí ó sì pe lọ sí orí ayélujára NCDC láti pé àkíyèsí wọn.Alix Fox,: O ṣe pàtàkì láti máa jẹ alábòójútó ẹni kejì wá àti fún àwa arawa, tí ó bá jẹ pe iwọ lọ rí àmì tí ó sì kó pé ó ti fi ẹnu kò àwọn ènìyàn lenu, ó ṣe pàtàkì kí je ki awon eniyan naa mọ, bti bá sì jẹ́ pé ìwọ náà lọ rí àmì lẹ́yìn tí ó fi ẹnu kò enikeni lẹ́nu, ó ṣe pàtàkì kí ó fi ara rẹ pamọ.
Èmi kii lọ rọba idaboobo ṣáájú asiko yii, njẹ mo lè bẹ̀rẹ̀ báyìí?
Alix Fox: Ìdáhùn yẹ nise pelu ìdí tí ó kii fi lọ roba ifaabobo tẹ́lẹ̀.To óò bá lọ roba idaboobo nítorí pé ìwọ àti enikeji rẹ tí ṣe ayẹwo pé eko ni a aarun tí ń tí ara ìbálòpọ̀ wáyé, tàbí ẹ ń lọ oogun tí kì je ki eniyan ni oyún tí ènìyàn kò fẹ́, ìyẹn dára, sugbon tó bá jẹ́ pé ó kii lọ roba idaabobo ni torí ó fi ọkàn sí pé ẹ ó máa faa yọ tàbí ẹ ń fọkàn sí pé ẹ ó lè ní aarun tó ń tí ara ìbálòpọ̀ mú ènìyàn, ó ṣe pàtàkì kí ẹ bere si lọ roba idaboobo ni asiko yii.

- Àjọṣepọ̀ wo ló wà láàrín Coronavirus àti Chloroquine? Ìdáhùn nìyíì
- Lílo nkan ìbomú kò tóò láti dènà pé kóò má á nìí coronavirus
- Àjọṣepọ̀ wo ló wà láàrín Coronavirus àti Chloroquine? Ìdáhùn nìyíì
- Ṣẹ́ lóòtọ́ ní ginger àti garlic lè pa àrun Coronavirus?
- Taye jẹ́ eni dúdú, Kehinde jẹ́ àfín; báwo ló ṣe jẹ́ bẹ́ẹ̀?

Ǹjẹ́ mo lè ni Coronavirus nípa fífi owó kan nkan obinrjn/ọkùnrin enikeji mi.
Dókítà Alex: Bí ẹ ó bá fi ọwọ kan nkan Obìnrin/Ọkùnrin enikeji rẹ, o ni lati je pe e tí ń fi ẹnu kò ara yín lẹ́nu, èyí sì ni góńgó orí rẹ nítorí ati ara ìtó ni aarun náà ń gba wo àgó ara nítorí náà ayé de fìdí láti gbé aarun náà fún enikeji, sugbon nkan ti ṣe pàtàkì jù ni pé ó ṣe pàtàkì kí olójú fe méjì wá lábé òrùlé kan náà, kí ẹ sì mọ ipò tí olúkúlùkù wa.
Báwo ni mo ṣe lè ní ololufe ni asiko yii, mi ò fe je apon lásìkò yìí.
Alix Fox: Oro ajakale aarun yìi tí ń mu kí òpó ènìyàn ronú bí wọn ṣe ni ìbálòpọ̀ tó dára ní òpò ìgbà àwọn miran ti wọn wa jí igbele gniyan láti kó leta ololufe sí ara wọn tí wón sì ni ìbálòpọ̀ tó dára lai fi ojú kan ara wọn. Èyí tí ń mú kí ọpọlọ ọgbọ́n atinuda wọn láti mú ìgbádùn bá ara wọn àti ololufe wọn.
Ǹjẹ́ àti ní aarun CORONAVIRUS tí tèmi ga ju ti ẹlòmíràn lọ tí mo bá ní aarun HIV
Alix Fox: Dókítà Michael Brady ni Terrance Higgins Trust tí fi àwọn imoran kán síta lórí èyí, tí ó bá jẹ pe oun lọ oogun rẹ loore koore nítorí aarun HIV tí sì jí CD4 tó dára èyí timo sì lè a ó lè ka ó mọ àwọn tí èròjà tó bá àìsàn woyaja rẹ kò lágbára tó, nítorí náà tí ó bá ní aarun HIV, tesiwaju láti máa lọ oogun rẹ kì o sì tẹ́lẹ̀ àwọn ìlànà tí ó yẹ bí ó bá ti ṣe alabapade ẹni tí ó ní aarun Coronavirus.












