Coronavirus: Ṣẹ́ lóòtọ́ ní ginger àti garlic lè pa àrun Coronavirus?

Àkọlé fídíò, Ṣẹ́ lóòtọ́ ní ginger àti garlic lè pa àrun Coronavirus?

Ọrọ coronavirus yi ti di tọrọfọnkale silẹ kaakiri gbogbo agbaye.

O ti di eyi ti awọn olori orilẹ-edefi n ṣaisun lelori.

Oriṣiriṣii awón igbagbọ ti iwadii ko fidiẹ mulẹ ni awọn eeyan ti n gbe jade.

Ọrọ alubọsa ayuu ati awọn ẹtalẹ funfun ati pupa yii naa jẹ ọkan nibẹ.