Africa eye: Ibi gbogbo là ń dáná alẹ́, ìwà jẹgúdújẹrá pa iléeṣẹ́ Spencom run ní Uganda

Àkọlé fídíò, Africa eye: Ibi gbogbo là ń dáná alẹ́, ìwà jẹgúdújẹrá pa iléeṣẹ́ Spencom run ní Uganda

Ọkan lara awọn odu ileeṣẹ kọngila lagbaye ni Spencom jẹ ki igba to yi pada fun wọn ni ọdun diẹ sẹyin.

Amọṣa, ikọ oju tole, oju toko ileeṣẹ BBC nilẹ Afirika ti a mọ si Africa eye tan ina wo idi iṣuna ileeṣẹ naa eleyi to fihan pe ọgbọ n run nidi awọn eeyan kan.

Atupalẹ rẹ niyi ninu fidio yii.