Obasanjo: Eré ìtàn nípa ìbí, àti jéèyàn pẹ̀lú ìpèníjà Olusegun Aremu Obasanjo

Bi a ba pori akọni nṣe laa fi ida lalẹ gaaraga.
Ko si bi eeyan ṣe lee darukọ orilẹ€de Naijiria ti a ko ni ranti oloye Oluṣẹgun okikiọla Arẹmu Ọbasanjọ.
- Oshiomole: irọ́ ni wọ́n ń pa,èmi ṣí ní Alága APC!
- Exclusive: Buhari ní àìlera lẹ́mìí, lára, àti lọ́kàn- Obasanjo
- 'Ti mo ba dara pọ mọ ẹgbẹ Obasanjọ, wọn gbọdọ yẹ mi lọpọlọ wo'
- Ilé iṣẹ ológun tú ọmọdé 223 afurasí agbébọn sílẹ ní àríwá Nàìjíríà
- Kí nìdí táwọn olùkọ́ ilé ìwé Federal Girls College Akure ṣe fí òkúta fọ́ ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́
- Exclusive: Atiku dára ju Buhari ní ìlọ́po méjì - Obasanjo #BBCNigeria2019
Ọmọ atapatadide to la oniruuru ipenija kọja lati de oke tente tabili irinajo rẹ laye.
Ajagunfẹyin, Ọgagunagba ati oloṣelu to dantọ ti gbogbo agbaye ko lee fọwọ rọ sẹyin ni Ọbasanjọ jẹ.
- Ilé aṣòfin Oyo àti Ogun buwọ́lu àbádòfin ikọ̀ aláàbò Amotekun
- Obìnrin tó ń ṣiṣẹ́ ẹrú ní Oman tó bá fẹ́ òmìnira, yóò bá ọ̀gá rẹ̀ ṣùn - obìnrin méjì tó ti oko ẹrú dé
- "Inú mi kìí dùn torí ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún mẹ́rin ni ọjọ́ ìbí mi máa ń wáyé"
- Kàyééfì ńla! Pẹ̀lúmi lu odindi ìlú kan ní jìbìtì ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ owó
- Ọkọ̀ dáńfó tí mò ń wà ní mo fi kọ́lé, rán ọmọ mẹ́ta ní fásitì - Obìnrin àkọ́kọ́ tó ń wa dáńfó l‘Eko
Ohun si ni ọmọ orilẹede Naijiria akọkọ ti yoo jẹ aarẹ gẹgẹ bii ologun ati gẹgẹ bii alagbada.
Ni ọjọ karun oṣu kẹta ọdun 1937 ni a bi Oloye Ọbasanjọ ni ilu Abẹokuta. Oni yi gan an si ni o pe ọdun mẹtalelọgọrin loke eepẹ.