Unity Bank: Kátàkára sí ń lọ nínú ọ̀gbà Banki náà

Banki
Àkọlé àwòrán, Lórí òpó Twitter Banki náà ni wọ́n ti sàlàye pé àwọn ko ti le fi idi rẹ̀ múlẹ̀ ǹkan to baje nínú ilé iṣẹ́ náà

Olú ilé iṣẹ́ Unity Bank ní agbègbè Victoria Island ni ilú Eko gbina lowuro òní.

Akọròyìn BBC tó sabewo síbẹ̀ sàlàyé pé kò si ẹni tó mọ ǹkan to fa idi ti ìnà fi ṣẹlẹ náà,

Ṣùgbọ́n gbogbo àwọn panápaná àti àwọn osiṣẹ alààbo míràn ti wà níkàlẹ lati fopin si.

Àkọlé fídíò, Unity Bank: Kátàkára sí ń lọ nínú ọ̀gbà Banki náà
Àkọlé fídíò, Yollywood: Kò sí ẹni ti òbí mi kò lè sọ̀rọ̀ sí -Sisi Quadri

Lórí òpó Twitter Banki náà ni wọ́n ti sàlàye pé àwọn ko ti I le fi idi nkan to faa mule.

osise ina

Oríṣun àwòrán, @lasema

Àkọlé àwòrán, Awọn oṣiṣẹ eleto aabo sa ipa wọn ;ati tete pa ina naa

Bakan naa ni wọn ko tii le sọ ni pato iye awọn ǹkan to baje nínú ilé iṣẹ́ náà, sùgbọ́n ìdùnù ló jẹ́ fún wa pé kò si ẹ̀mi to sọnu ninú ìṣẹ̀lẹ̀ náà.

adugbo
Àkọlé àwòrán, Won ti pa ina naa aw#on osise si ti bere ise won pada

Wọ́n fi kún pé àwọn oṣiṣẹ́ àwọn si n da àwọn onibara lohun nitori pe gbogbo ko si ìdànmú to kan agbègbè rẹ̀.

banki
Àkọlé àwòrán, Awọn agbofinro ipinlẹ Eko duro wamu lati fopin si banki naa to n jona.
osise ina
Àkọlé àwòrán, Bakan naa ni won tun di ona to wo adugbo naa pa ki awon eniyan ma le kagbako ina
ina
Àkọlé àwòrán, Aw#on panapana sisie daadaa lati tete pa ina naa
moto

Oríṣun àwòrán, @LASEMA

Àkọlé àwòrán, Lara mọtọ to jona ninu iṣẹlẹ ọhun
Àkọlé fídíò, Yollywood:Ṣàgbẹ̀lójú yòyò ni ọ̀ps àwọn òṣèré- Ojopagogo