Niger Flood: Omíyalé àgbàrà ti ya ṣọ́ọ̀bù ní Niger

flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Kirkissoye ti kun fun omi ti aya awọn agbegbe naa n ja bayii

Bi ojo ṣe n rọ lasiko yii ni orilẹ-ede Naijiria ti ẹru omiyale n ba awọn eniyan bẹẹ naa ni ojo naa n rọ ni orilẹ-ede Niger.

Ojo arọọroda to rọ ni ọjọ kẹta, oṣu kẹsan an ọdun yii lo n jẹ ki ọkan awọn obinrin yii ma balẹ ni agbegbe Kirkissoye ni Niamey.

flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọde n wa ọna abayọ si omi to n ya wọnu ile obi wọn

Orọ omiyale agbara ya ṣọọbu yii ko yọ awọn ọdọmọde silẹ ni Naimey.

Awọn naa lọ n gbọ́n iyẹpẹ fi di awọn ibi ti omu ti gba opopona to si ti n ya wọnu ile.

flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Opọ ero lawọn oṣiṣẹ eleto aabo ti doola ẹmi wọn kuro ninu agabra ojo yii

Awọn oṣiṣẹ ileeṣe panapana ni orilẹ-ede Niger ti ko awọn eniayna kuro ni Niamey to jẹ olu ilu Niger.

won ko won lọ si ibudo ti omi ko pọ si .

Àkọlé fídíò, Omiyale Ile Ife: Dukia sọfọ, awọn eniyan si tun farapa
flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Agbara omiyale pọ, ko si ibi ti ko le wo.

Ara agbegbe Kirkissoye kan ni yi ni Niamey to n wo ile rẹ ti omi ya wọ ti ko si si nkan to le ṣe.

flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọdọmọkunrin kan ree to n rin lojri omi ni ọna Kirkissoye.
flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, ọpọ ero ni wọn ko ri ọna wọle wọn mọ lẹyin ti omi ti gab gbogbo oju ọna
flood

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn oṣiṣẹ panapana n wa ojutu si iṣoro awọn eniyan Niamey.

Akọsilẹ to peye ni wọn n ṣe fun ohun to nilo ati awọn to yẹ fun ipese fawọn to lugbadi omiyale.

Àkọlé fídíò, È gbọ òun ti ojú awọn ara ipinle Ogun rí lọwọ ìṣẹlẹ omiyale