Ìpàdé àwọn orílẹ̀èdè G7:Trump lòdì sí àbájáde ìpàdé

Sáájú, Ààrẹ Trump ti sáájú buwọ́lù àbájáde ìpàdé náà ṣùgbọ́n o yí ìpinu rẹ pàdà
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Donald Trump ti yí ọrọ pàdà lórí àbájáde ìpàdé àwọn orílè-èdè G7 ti o tí sáájú buwọ́lù.

Oríṣun àwòrán, Reuters
Trump fí ọrọ̀ ìyípadà náà lédè lójú òpó Twitter pẹlú àlàyé pé àwọn orílè-èdè tó kù n fí owo orí ọjà tó ga lè Amẹrika.








