Àwọn ọ̀dọ́ orílẹ̀èdè Nàìjíríà sọ èrò wọn lórí Nàìjíríà
Owe agba lo sọ pe Oriṣa ti baba ba sin ti ko fi han ọmọ, kii pẹ parun.
Awọn ọdọ orilẹede Naijiria ti pari sita pe awọn naa ni ọrs lati sọ o. Idi gan niyi ti BBC News Yoruba fi gbe wọn wa si gbagede ọrs lori bi nnkan ṣe n lọ lorilẹede Naijiria ati ero wọn lori
rẹ.
- Láì ṣe pé Naijiria pín síjọba ẹlẹ́yàmẹ̀yà, kó sí ètùtù ọ̀nà àbáyọ -Afẹnifẹre
- Àwọn àwòrán ọlọkan o jọkan tí ń tọka àyájọ òmìnira Nàìjíría
- Ilẹ China ń sàmì àádọrin ọdun tí wọn gbòmìnira pẹ̀lú ìfẹ̀hònúhàn
- Ẹ wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká olórin, òsèré tó ti sàtìmọ̀lé rí!
- Wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀ níbi ayẹyẹ àyájọ́ ọdún òmìnira ní ìpínlẹ̀ Oyo
- À ṣé olóòrùn ni ayálégbé mi tó ń fojóojúmọ́ ṣakọ lórí ayélujára- Onílé Lisa Li
- Àtìpó 161 míì dé padà láti Libya layajọ́ ominira Naijiria
- Ìwà pẹ̀lẹ́ àti iṣẹ́ takuntakun ló mú mi ṣàṣeyorí- Pryce